Àwọn agbésùmọ́mí ti dé ẹnu-ọ̀nà mi-Enoch Adeboye Olùdásílẹ̀ ìjọ Redeem sọ̀rọ̀.

Àwọn agbésùmọ́mí ti dé ẹnu-ọ̀nà mi, Adeboye sọ̀rọ̀ yìí ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kandílọ́gbọ̀nOṣu Kẹfa Ọdun 2026 4:21 irọlẹ Alábóòjútò Gbogbogbo Olùdásílẹ̀…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fidi rẹ mulẹ pé àwọn Boko Haram ti jí àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ to ń kọ ìdánwò Neco gbe lọ ,tí wọ́n sì pa awọn olùkọ́ nínú ìkọlù tó wáyé ní Borno.

Àwọn ọlọ́pàá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fidi rẹ mulẹ pé àwọn Boko Haram ti jí àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ to ń kọ ìdánwò…

Ka siwaju

Àwọn agbésùmọ́mí Boko Haram yawọ ilé ìwé girima, yìnbọn pa olùkọ́ ti wọn sì jí ọ̀pọ̀ Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ to ń kọ ìdánwò Neco gbé lọ ní agbègbè Borno.

Àwọn agbésùmọ́mí Boko Haram yawọ ilé ìwé girima, yìnbọn pa olùkọ́ ti wọn sì jí ọ̀pọ̀ Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ to ń…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá Metro bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ “Kosaye” ní ìpínlẹ̀ Ogun, Èkó,wọ́n mú àwọn afurasi ọ̀daràn agbésùmọ́mí 88, wọ́n sì gba àwọn tí wọ́n jí gbé márùn-ún sílẹ̀.

Àwọn ọlọ́pàá Metro bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ “Kosaye” ní ìpínlẹ̀ Ogun, Èkó,wọ́n mú àwọn afurasi ọ̀daràn agbésùmọ́mí 88, wọ́n sì gba àwọn…

Ka siwaju

Àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà , àwọn oludije ti won yan láti ìpínlẹ̀ Imo lọ sí Zaria ni ìjàmbá ọkọ ojú -ọna, ọpọlọpọ àwọn ọmọ ogun lo farapa yánnayànna .

Awọn ọmọ-ogun Naijiria, awọn oludije ti o yan láti ìpínlẹ̀ Imo ni ijamba ọkọ oju-ọna ti o lọ si Zaria,…

Ka siwaju

Ìjọba Tinubu jẹwọ owó-iṣẹ oṣù ti o kéré julọ N70,000 Ko tó fún ọrọ-aje mọ, wọn ṣe àwọn ifihan si àwọn ìjíròrò tuntun lórí owó òṣìṣẹ́ .

Gbajiamila ṣe ìfihàn náà ní ọjọ́rú nígbí tí ó ń ṣojú fún Ààrẹ Tinubu níbi ìpàdé ìjọba tí Working People…

Ka siwaju

Awọn Agbésùmọ́mí ṣe Ìkọlù sí eléso ààbò ìrù ẹkùn Sunday Igboho ní igbó Ọyọ àtijó National Park , ọpọlọpọ farapa yánnayànna.

Àwọn onijagidijagan Agbésùmọ́mí ṣe Ìkọlù sí eléso irú ẹkùn Sunday Igboho’s ní igbo Ọyọ àtijó National Park , ọpọlọpọ farapa…

Ka siwaju