Ṣé wọ́n ń fún àwọn ọmọ eleso ààbò figilantes ní irú ohun ìjà tó wúwo báyìí?’: Àwọn Akọ̀wé Àríwá pe àwọn ọlọ́pàá níjà pé àwọn ọkùnrin tó di ìhámọ́ra ogun wọ̀ pẹ̀lú orisirisi ohun ìjà lọwọ nínú fídíò tó jáde síta lórí ayélujára ni Katsina jẹ́ ọmọ eléso ààbò figilantes.

Ṣé wọ́n ń fún àwọn ọmọ eleso ààbò figilantes ní irú ohun ìjà tó wúwo báyìí?’: Àwọn Akọ̀wé Àríwá pe…

Ka siwaju

Àwọn agbésùmọ́mí kọ́ ló wà nínú fọ́nrán tí ara ìlú ń gbé kiri lórí ayélujára àwọn ọdẹ figilantes ní – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Nàìjíríà takò fọ́nrán náà.

Àwọn agbésùmọ́mí kọ́ ló wà nínú fọ́nrán tí ara ìlú ń gbé kiri lórí ayélujára àwọn ọdẹ figilantes ní –…

Ka siwaju

Àwọn jàǹdùnkú olóṣèlú pa olórí ọ̀dọ́ ẹgbẹ Accord Esa-Oke Ọ̀sun, Gómìnà Adeleke pé Komisona ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ọ̀sun Wole Oke, Oyetola, Oyebamiji àti àwọn mìíràn fún apero, ṣe abewo sí àwọn ẹbí .

Gomina Adeleke pe Komisana olopaa, Wole Oke, Oyetola, Oyebamiji, ati awon mi-in nitori ipaniyan òṣèlú ìpínlẹ̀ Ọ̀sun Gomina Ademola Adeleke…

Ka siwaju

Ilé-igbimọ aṣojú sòfin àgbà L’abuja ti ṣe àtúnṣe ikẹhin òfin lati fi idi ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ ni Nàìjíríà múlẹ̀.wọn bẹ̀rẹ̀ Jomitoro ọ̀rọ̀ lórí owó ọlọ́pàá ìpínlẹ̀.

Ilé ìgbìmò aṣojú sòfin àgbà L’abuja bẹrẹ Jomitoro ọ̀rọ̀ lórí owó ọlọ́pàá ìpínlẹ̀. Àwọn ilé ìgbìmọ̀ asoju asofin Labuja tí…

Ka siwaju

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tí kéde isede òfin konile gbele òní -wákàtí mẹ́rìndínlógún (16hrs) ni agbègbè Ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́wàá 10.

Ijoba Oyo kéde isede òfin konile gbele òní -wákàtí mẹ́rìndínlógún (16hrs) ni gbogbo agbègbè Ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́wàá 10. Oṣu Kẹfa…

Ka siwaju

Olórí Bandit Turji Bello sọ pé òun ló ṣe ikọlu sí àwọn oṣiṣẹ eléso ààbò ọmọ ogun Nàìjíríà ni Zamfara, Sokoto nínú fídíò tuntun tó gbé síta.

Olórí Bandit Turji Bello sọ pé òun ló ṣe ikọlu sí àwọn oṣiṣẹ eléso ààbò ọmọ ogun Nàìjíríà ni Zamfara,…

Ka siwaju