Àwọn olóyè ilẹ̀ Ìbàdàn rọ olùdíje fún ipò Gómìnà Ọ̀yọ́ lábẹ́ asia ẹgbẹ́ APC Alli Sharafadeen láti ṣe pàtàkì ipá ti oyè ìbílẹ̀ ju erongba olóṣèlú lọ.

Àwọn olóyè rọ olùdíje fún ipò Gómìnà Ọ̀yọ́ lábẹ́ APC Alli Sharafadeen láti ṣe pàtàkì ipá ti oyè ìbílẹ̀ ju…

Ka siwaju

Ọba Salman Aweda tìlú Olayinka ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí tí won jigbe ni ijoba ìbílẹ̀ Ifelodun Kwara, lẹ́yìn ti awon ajinigbe béèrè fun Milionu mọ́kànlélógún náírà , ọ̀kadà Alùpùpù méjì àti epo Petiro.

Ọba Salman Aweda tìlú Olayinka ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí tí won jigbe ni ijoba ìbílẹ̀ Ifelodun Kwara,…

Ka siwaju

Arìnrìn àjò Ìròyìn bí ó ṣe sá àsálà fún ẹ̀mí rẹ bí àwọn agbésùnmọ̀mí ṣe kọlù Nítòsí Ọgbà Ọ̀yọ́ àtijọ́ “Old Oyo National Park”.

Arìnrìn àjò Ìròyìn bí ó ṣe sá àsálà fún ẹ̀mí rẹ bí àwọn agbésùnmọ̀mí ṣe kọlù Nítòsí Ọgbà Ọ̀yọ́ àtijọ́…

Ka siwaju

Gómìnà Katsina Radda ní kí àwọn agbésùnmọ̀mí gbé ohun ìjà ọwọ́ wọn sílẹ̀, kí wọ́n padà sí ọ̀dọ̀ àwọn ẹbí wọn gẹ́gẹ́ bí ìjọba ṣe ṣèlérí àtitìlẹ́yìn.

Gómìnà Katsina Radda ní kí àwọn agbésùnmọ̀mí gbé ohun ìjà ọwọ́ wọn sílẹ̀, kí wọ́n padà sí ọ̀dọ̀ àwọn ẹbí…

Ka siwaju

Ọ̀gá àgbà Gen. Rabe Abubakar Agbẹnusọ fún iléeṣẹ́ Ologun Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí, tí wọ́n jí gbé pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀ ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí.

Ọ̀gá àgbà Gen. Rabe Abubakar Agbẹnusọ fún iléeṣẹ́ Ologun Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí, tí wọ́n jí gbé pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀ ti…

Ka siwaju