Ọọ̀ni Adeyeye Eniitan Ogunwunsi Ọ̀jájá 11 tí késí ìjọba àpapọ̀ láti fòpin sí ètò àbò tó mẹ́hẹ àti bí ìwà jagidijagan àwọn ìwà ọ̀daràn mìíràn ṣe ń dàgbàsókè si lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Ọọ̀ni Adeyeye Eniitan Ogunwunsi Ọ̀jájá 11 tí késí ìjọba àpapọ̀ láti fòpin sí ètò àbò tó mẹ́hẹ àti bí ìwà…

Ka siwaju

Ìjọba ìpínlẹ̀ Borno tí bójú àànú wo àwọn agbésùnmọ̀mí Oòkóléní Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin 720 àti àwọn tó jẹ́ alátìleyìn fún wọn 992 pẹ̀lú àwọn ọmọ wọn 2,050 ni wọn dapadà sínú Awujọ.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Borno tí bójú àànú wo àwọn agbésùnmọ̀mí Oòkóléní Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin 720 àti àwọn tó jẹ́ alátìleyìn fún wọn 992…

Ka siwaju

Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu pàṣẹ fún gbogbo àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà lati gba awọn ọkọ ayọkẹlẹ ti wọn ko ni nọmba ni gbogbo orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu pàṣẹ fún gbogbo àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà lati gba awọn ọkọ ayọkẹlẹ ti wọn ko ni nọmba…

Ka siwaju

Ọga agba iléèwé Ọyọ ti wọn jigbe pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sọ pé kii sẹ owo biliọnu kan naira,ọkọ̀ Hilux méjì àti òfin Sharia ni àwọn agbesunmobi ń bèrè fún ò.

Ọga agba ileewe Ọyọ ti wọn jigbe pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sọ pé kii sẹ owo biliọnu kan naira,ọkọ̀ Hilux méjì…

Ka siwaju

Orílẹ̀ èdè Iran ṣe ìfọlọ́lè àwọn misaili tuntun fún Israeli fún ìgbà àkọ́kọ́ láti inú oṣù kẹrin àdéhùn jogunomi ni àárín Ìlà-Oòrùn.

Iran ṣe ifilọlẹ awọn misaili tuntun fún Israeli fun igba akọkọ lati inú oṣù kẹrin àdéhùn jogunomi ni àárín Ìlà-OòrùnỌjọ́…

Ka siwaju