Ilé-ẹjọ́ ìjọba àpapọ̀ L’abuja paṣẹ kí wọ́n yọ Iforukọsilẹ ti ẹgbẹ́ òṣèlú ADC,ẹgbẹ Accord,àwọn ẹgbẹ Òṣèlú Mẹta mìíràn kúrò.

Ilé-ẹjọ́ ọ ìjọba àpapọ̀ L’abuja paṣẹ kí wọ́n yọ Iforukọsilẹ ti ẹgbẹ́ òṣèlú ADC,ẹgbẹ Accord,àwọn ẹgbẹ Òṣèlú Mẹta mìíràn kúrò.…

Ka siwaju

Olùdíje fún ipò Gómìnà Ọ̀yọ́ lábẹ́ asia ẹgbẹ́ òṣèlú Accord , Oriyomi Hamzat, Tako ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn pé ó ní àwọn ọna asopọ Kan si Afurasí adigunjalè ‘Surri Ilupeju’.

Olùdíje fún ipò Gómìnà Ọ̀yọ́ lábẹ́ asia ẹgbẹ́ òṣèlú Accord , Oriyomi Hamzat, Tako ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn pé…

Ka siwaju

Àwọn asofin ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Kọ̀ jálẹ̀ láti dúnàdúrà pẹ̀lú àwọn agbéṣùmọ̀mí tó jí àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọ́ gbé lọ ní ìjọba ìbílẹ̀ Oriire ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Àwọn asofin ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Kọ̀ jálẹ̀ láti dúnàdúrà pẹ̀lú àwọn agbéṣùmọ̀mí tó jí àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọ́…

Ka siwaju

Seyi Makinde bu ẹnu atẹ lu awọn ọrọ ti Fayose sọ , lórí àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọtí àwọn agbésùmọ́mí jí gbé ní Ọ̀yọ́, o rọ ara ilu kí wọn gbàdúrà fun un.

Makinde bu ẹnu atẹ lu awọn ọrọ ti Fayose sọ , lórí àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọ́ tí…

Ka siwaju

Idunnu nla ṣubú layọ̀ ni olu ilé-iṣẹ́ APC lórí bí Tinubu ṣe jáwé olubori nínú ètò ìdìbò abẹ́lé fún ipò Ààrẹ orílẹ̀ Nàìjíríà .

Lónìí tíì ṣe ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọjọ́ ketalelogun oṣù Kàrún ọdún 2026 yii, ní Nàìjíríà dibo abẹ́lé fún ipò Ààrẹ orílẹ̀…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí nílò owó láti dá àbó bó ara wọn lọ́wọ́ ipa ìjọba Nàìjíríà tó fẹ́ pa wọn ló jẹ́ kí wọ́n ma ṣe ìkọlù sí àwọn ìletò, jí àwọn ará ìlú gbé – Agbẹnusọ fún àwọn- agbésùnmọ̀mí Sheikh Gumi

Agbenusọ fún àwọn agbésùnmọ̀mí Islam kan, Sheikh Ahmad Gumi, ti sọ idi ti awọn darandaran ko fi le kuro nìdí…

Ka siwaju