Àwọn ọlọ́pàá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fidi rẹ mulẹ pé àwọn Boko Haram ti jí àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ to ń kọ ìdánwò Neco gbe lọ ,tí wọ́n sì pa awọn olùkọ́ nínú ìkọlù tó wáyé ní Borno.

Àwọn ọlọ́pàá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fidi rẹ mulẹ pé àwọn Boko Haram ti jí àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ to ń kọ ìdánwò…

Ka siwaju

Awọn ọmọ ile-iwe ń ṣubu lulẹ̀ lakoko ayẹyẹ àyájọ́ Ọjọ Awọn ọmọde, Ọ̀pọ̀ àwọn ọmọdé, ọmọ ilé ìwé ló dákú, bí wọn ṣe yín Tajútajú nibi ayẹyẹ àyájọ́ Awọn ọmọde ni . Edo.

Iberu lo wa ni papa isere Samuel Ogbemudia, lojoru Wesde, nigba ti a gbo wi pe awon akekoo kan subu…

Ka siwaju

Ẹ na ẹnikẹ́ni tí ó bá tako òfin Sharia, Mufti tí Ìlú Iwo, Sheikh Daood Imran Molaasan ti rọ àwọn Mùsùlùmí láti na ẹnikẹ́ni ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tí ó bá tako ìdásílẹ̀ òfin Sharia.

Mufti ti ìlú Iwo, Sheikh Daood Imran Molaasan, ti ro àwọn Mùsùlùmí lati lu ẹnikẹ́ni ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti o…

Ka siwaju

Wọn pa ènìyàn Mẹta ,jí àwọn Mẹ́ẹ̀dógún gbé lọ Bi awọn agbebọn ṣe kọlu àwọn ènìyàn to lọ ṣe àdúrà ni orí òkè Ìjàyè n’ilu Ekerin ìjọba ìbílẹ̀ Ekiti Kwara.

Gẹ́gẹ́ bi ọlọ́pàá ṣe fìdí ìròyìn náà múlẹ̀ pé , ìkọlù náà wáyé ni ọjọ Àbámẹ́ta ọjọ́ ketalélógún, Oṣu Karun…

Ka siwaju

Ilé funfun Amerika wà lábẹ́ ewu ńlá :ọ̀pọ̀ ìbọn ń ró lakolako bí àwọn bí àwọn agbébọn kan ṣe yawọ agbègbè ilé funfun Amẹ́ríkà ti wọn fẹ pa Ààrẹ Trump.

Ilé funfun Amerika wà lábẹ́ ewu ńlá :ọ̀pọ̀ ìbọn ń ró lakolako bí àwọn bí àwọn agbébọn kan ṣe yawọ…

Ka siwaju

Idunnu nla ṣubú layọ̀ ni olu ilé-iṣẹ́ APC lórí bí Tinubu ṣe jáwé olubori nínú ètò ìdìbò abẹ́lé fún ipò Ààrẹ orílẹ̀ Nàìjíríà .

Lónìí tíì ṣe ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọjọ́ ketalelogun oṣù Kàrún ọdún 2026 yii, ní Nàìjíríà dibo abẹ́lé fún ipò Ààrẹ orílẹ̀…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí fi Lẹ́tà ránṣẹ́ dúnkokò mọ́ àwọn ilé ìwé ni ijoba ìbílè Odeda ni ìpínlẹ̀ Ogun, pé àwọn ń bọ̀ láti jí wọn gbé , àwọn ọdẹ àdúgbò pariwo síta

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí fi Lẹ́tà ránṣẹ́ dúnkokò mọ́ àwọn ilé ìwé ni ijoba ìbílè Odeda ni ìpínlẹ̀ Ogun, pé àwọn ń…

Ka siwaju