ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé àwọn ọkọ̀ òfuurufú méjì tí wọ́n rà fún iṣẹ́ àbò àti láti mú kí gbígbà ìròyìn àṣírí nípa ọ̀rọ̀ àbò láàrin ìpínlẹ̀ náà túbọ̀ lágbára ti dé. Asake Jul 28, 2026 0 Gómìnà Makinde sọ pé wọ́n ra ọkọ̀ òfuurufú náà láti lè máa gba ìwífún láti ojú ọ̀run káàkiri Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́;… Ka siwaju