ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ Sheikh Gumi bèrè ìdí tí kò fi sí òṣìṣẹ́ Ìjọba Tinubu kankan tí ó ti lọ pàdé awọn ọmọ ẹgbẹ ikọ̀ Boko Haram tàbí lọ bá àwọn ọlọ́ṣà agbésùmọ́mí fún ijiroro ìpàdé àlàáfíà , gẹ́gẹ́ bí Jonathan àti Osinbajo ti ṣe pẹ̀lú àwọn ọlọ̀tẹ̀ oníjàgídíjàgan agbègbè Niger Delta (Niger Delta militants) . Asake Jul 26, 2026 0 Sheikh Gumi bèrè ìdí tí kò fi sí òṣìṣẹ́ Ìjọba Tinubu kankan tí ó ti lọ pàdé awọn ọmọ ẹgbẹ… Ka siwaju