Tinubu sọ fún Gómìnà Ademola Adeleke lórí ìpè fóònù pé òun ti pàṣẹ fún EFCC láti ṣí àkọọ́lẹ̀ ifowopamo owó ìjọba ìpínlẹ̀ Osun tí wọ́n ti pa tẹ́lẹ̀ sílẹ̀ .

Tinubu sọ fún Adeleke nípasẹ̀ ìpè lórí fóònù pé òun ti pàṣẹ fún EFCC láti ṣí àkọọ́lẹ̀ ifowopamo owó ìjọba…

Ka siwaju