Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu ti gbẹ́ṣẹ́ lé awọn oniṣẹ POS tó má ń jòkó sí ẹgbẹ́ àgọ́ ọlọ́pàá ní gbogbo Nàìjíríà lórí àwọn ẹ̀sùn Ìlọ́nilọ́wọ́gbà tí wọ́n fi kan àwọn ọlọ́pàá

IGP Ọ̀gá ti gbẹ́ṣẹ́ lé àwọn oníṣẹ́ POS tó ma ń jòkó sí ẹgbẹ́ àgọ́ ọlọ́pàá ní Nàìjíríà Nàìjíríà, ó…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu rán gbákejì rẹ̀ Kashim Shettima lọ sí Ondo fún ti ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọgọ́rùn-ún ọdún DR. Reuben Fasoranti.

Igbákejì Ààrẹ Nàìjíríà Kashim Shettima dé sí Ondo fún ti ayẹyẹ ọgọ́rùn-ún ọdún ọjọ́ ìbí Reuben Fasoranti. Igbákejì orílẹ̀ èdè…

Ka siwaju

Mínísítà tuntun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn fún iná mọ̀nàmọ́ná Joseph Tegbe figbe ta, Mi kò ṣèlérí pé iná yóò fún oṣù mẹ́ta fún ọmọ Nàìjíríà o.

Minisita ti wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ yan fun Agbára iná mànàmáná , Joseph Olasunkanmi Tegbe, ti kọ awọn iroyin ti o sọ…

Ka siwaju

Peter obi lára àwọn oludije fún ipò Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ti kéde ìfipòslẹ̀ rẹ̀ nínú ẹgbẹ́ òṣèlú African Democratic Congress ADC.

Peter obi ọ̀kan lára àwọn Oludije fún ipo Ààrẹ Nàìjíríà, ti kéde ifiposile re nínú ẹgbẹ́ òṣèlú African Democratic Congress…

Ka siwaju

Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano fún arábìnrin Naseer Teemahcool ni ipò òṣèlú gẹ́gẹ́ bí alámójútó ètò àwọn obìnrin lẹ́yìn tí ó ṣe àfihàn àwọ̀tẹ́lẹ̀ obìnrin pátá ni níbi ìpolongo ìdìbò 2027 ni Kano.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano tí fún Fatima Naseer Teemahcool, Alaga ti Gida-Gida TikTokers ti o ṣe afihan awọn aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ obìnrin…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu ti buwọ́lu N2bn owó gbà má bínú àtìlẹyìn ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn 27 tí àwọn agbésùnmọ̀mí pa ni March 29,ọjọ́ ìsinmi ọ̀pẹ (palm Sunday) ní Plateau .

Ààrẹ Bola Tinubu ti buwọ́lu N2bn ni àtìlẹyìn iranlọwọ owó gbà má bínú fún àwọn olóògbé 27 tí àwọn agbésùnmọ̀mí…

Ka siwaju