Àwọn ẹlẹ́ṣọ àbò Aṣọ́gbó ti farapa yannayanna,Won pa ènìyàn méjì, tí wọ́n sì tún jí àwọn aráàlú gbé lọ ní ọsan gangan nígbà tí àwọn agbésùnmọ̀mí kọlù Oko Erese oro- àgọ́, Babanla Kwara.

Awọn ará ìlú ti o ba oníròyìn sọrọ sọ pe ìṣẹ̀lẹ̀ náà wáyé ni ọsan ọjọ ìṣẹ́gun, ọjọ́ kejìdnlogbon oṣù…

Ka siwaju

Àwọn agbébọn yawọ ilé ìjọsìn Christ Apostolic church Eda Oniyo ní ìpínlẹ̀ Èkìtì, wón pa Pásítọ̀ ìjọ, wọ́n jí ọ̀pọ̀lọpọ̀ olùjọsìn gbé lọ.Ní dédé ago mẹ́jọ àbọ̀ àṣálẹ́8:30pm, ọjọ́ ìṣẹ́gun .

Àwọn agbébọn yawọ ilé ìjọsìn Christ Apostolic church Eda Oniyo ní ìpínlẹ̀ Èkìtì, wón pa Pásítọ̀ ìjọ, wọ́n jí ọ̀pọ̀lọpọ̀…

Ka siwaju

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀sun ti rọ Ọba Gbenga Oloyede tìlú Ipetumodu lóye, látàrí ẹ̀sùn jìbìtì owó COVID19 tí ó gbé ọba lọ ẹ̀wọ̀n L’ámẹ́ríkà.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀sun ti gbé Ọba Gbenga Oloyede kúrò lórí ìtẹ́ ọba gẹ́gẹ́ bí Apetumodu ti Ipetumodu ni ìjọba ìbílẹ̀…

Ka siwaju

Arábìnrin Shifawu Alabi ẹni Àádọ́rin Ọdún tó sọnù ni ọjà ọba Ìbàdàn ni wọ́n rí ní Ọ̀sun iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ ọ̀sun ló kéde rẹ̀.

Arábìnrin ìyá àgbàlagbà kan ẹni Àádọ́rin Ọdún Shifawu Alabi tí ó sọnu tí àwọn ẹbí ń wá ní Ọjà ọba…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí yawọ ìlú Rafiu Ajakaye olórí àwọn akọ̀ròyìn fún Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara.Wón jí ènìyàn mọ́kànlá gbé lọ nínú ilé rẹ̀ ìjọba ìbílẹ̀ Ifelodun Kwara.

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí yawọ ìlú Rafiu Ajakaye olórí àwọn oníròyìn fún Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara.Wón jí ènìyàn mọ́kànlá gbé lọ nínú ìlú…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí jí arabinrin kan Olanike Ogundare gbé lọ nínú ilé rẹ ní ìpínlẹ̀ Èkó.Wọn kí àwọn ẹbí rẹ san N60Millionu owó ìtúsílẹ̀ rẹ.

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí jí arabinrin kan gbé lọ nínú ilé rẹ L’eko, lẹ́yìn ti wọ́n borí àwọn ẹlẹ́ṣọ àbò agbègbè náà…

Ka siwaju

Ọwọ́ iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Èkó ti tẹ ọlọ́pàá tó n gba owó rìbá lọ́wọ́ àwọn awakọ̀, onikẹ̀kẹ́ maruwa, ọlọ́kadà ní Idimu L’eko.

Ọwọ́ Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Èkó ti tẹ ọlọ́pàá 👮👮‍♂️ tó ń gba rìbá lọ́wọ́ àwọn oni Kẹ̀kẹ́nape ,awakọ̀,ọlọ́kadà ,🚴‍♂️ onímaruwa…

Ka siwaju