Àwọn olùkọ́ ní Morocco béèrè fún ìsinmi ọjọ́ Sátidé, iṣẹ́ wákàtí mẹ́jọ ní ọ̀sẹ̀ nínú ìfẹ̀hónúhàn tuntun

Àwọn olùkọ́ tí wọ́n ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Ẹgbẹ́ Ẹ̀kọ́ Orílẹ̀-èdè Morocco ṣe àtakò níta Ilé-iṣẹ́ ẹ̀ka ètò Ẹ̀kọ́ ní ọjọ́…

Ka siwaju

Lórí ọ̀rọ̀ Ìjínigbé: MACBAN bẹ Gómìnà Ọ̀yọ́ , Makinde, fi ẹ̀sùn kan Sunday Igboho fún fífi ìwé àṣẹ sílẹ̀ láti halẹ̀ mọ́ àwùjọ Fulani.

Lórí ọ̀rọ̀ Ìjínigbéc: MACBAN bẹ Gómìnà Oyo, Makinde, fi ẹ̀sùn kan Sunday Igboho fún fífi ìwé àṣẹ sílẹ̀ láti halẹ̀…

Ka siwaju

Ilé ẹjọ́ pàṣẹ fún àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà láti gbé ẹjọ́ sájẹ́ǹtì ọlọ́pàá tí ó pa Kabiru awakọ, kí wọ́n sì san owó ìtanràn igba mílíọ̀nù náírà N200M fún pípa awakọ̀ ọkọ̀ akẹ́rù Kabiru Babai ní ọdún 2021 ní ìpínlẹ̀ Osun.

Ilé ẹjọ́ pàṣẹ fún àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà láti gbé ẹjọ́ sájẹ́ǹtì, kí wọ́n sì san owó mílíọ̀nù igba N200M fún…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ondo dojú ìjà kọ àwọn agbésùmọ́mí ajínigbé,wọ́n da ìbọn bolẹ̀ wọ́n sì gba ìyà àgbà obìnrin ọmọ ọdún mọ́kànlélọ́gọ́ta là nílu Ọwọ.

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ondo kojú ìjà, da ìbọn bolẹ̀ fún àwọn agbésùmọ́mí ajínigbé, wọ́n sì gba ìyà àgbà obìnrin…

Ka siwaju