ÀWỌN ÌRÒYÌN TÍ Ó NÍPA Ọmọ ẹni ti o da ile-iṣẹ ọ̀kín bisikiiti silẹ sọrọ nipa iroyin ipadabọ awọn bisikiiti OkinIle-iṣẹ Okin Industries sọ pe awọn ṣe ìgbìyànjú lati tun mu ami-ọja bisikiiti Okin ti o gbajumọ pada wa si ipo rẹ ṣi n lọ lọwọ, eyi ti o n funni ni ireti pe yoo pada wa si orilẹ-ede Naijiria gẹgẹ bi ọpọlọpọ ti n reti rẹ láìpẹ́ . Asake Jul 25, 2026 0 Ọmọ ẹni ti o da ile-iṣẹ naa silẹ sọrọ nipa iroyin ipadabọ awọn bisikiiti OkinIle-iṣẹ Okin Industries sọ pe awọn… Ka siwaju