Awọn onijagidijagan Agbésùmọ́mí ti o di ihamọra pa awọn ọmọkunrin meji Alaga ẹgbẹ Miyetti Allah ni agbegbe Gusu-ila-oorun, wọn si pa awọn malu rẹ̀ ogójì 40 ni agbegbe kan ni Enugu.

Awọn onijagidijagan Agbésùmọ́mí ti o di ihamọra pa awọn ọmọkunrin meji Alaga ẹgbẹ Miyetti Allah ni agbegbe Gusu-ila-oorun, wọn si…

Ka siwaju

Ọlọ́pàá Nàìjíríà ti jẹ́rìí sí ìtúsílẹ̀ àwọn olùjọ́sìn CAC Eda Oniyo ní Ìpínlẹ̀ Ekiti lẹ́yìn tí wọ́n ti lo oṣù mélòó kan pẹ̀lú nínú ìgbèkùn àwọn agbésùnmọ̀mí.

Ọlọ́pàá Nàìjíríà ti jẹ́rìí sí ìtúsílẹ̀ àwọn olùjọ́sìn CAC Eda Oniyo ní Ìpínlẹ̀ Ekiti lẹ́yìn tí wọ́n ti lo oṣù…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fidi rẹ mulẹ pé àwọn Boko Haram ti jí àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ to ń kọ ìdánwò Neco gbe lọ ,tí wọ́n sì pa awọn olùkọ́ nínú ìkọlù tó wáyé ní Borno.

Àwọn ọlọ́pàá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fidi rẹ mulẹ pé àwọn Boko Haram ti jí àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ to ń kọ ìdánwò…

Ka siwaju