ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ Àjọ tó ń kojú ọ̀rọ̀ oògùn olóró ní Nàìjíríà NDLEA mú obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Chad kan tó jẹ́ ẹni ọgọ́rin ọdún , tí wọ́n sì ń fẹ̀sùn kàn pé ó ń ta oògùn olóró, nígbà tí wọ́n ń ṣe ìgbésẹ̀ kárí-ìlẹ̀ láti dènà irú ìwà bẹ́ẹ̀. Asake Jul 19, 2026 0 Àjọ tó ń kojú ọ̀rọ̀ oògùn olóró ní Nàìjíríà NDLEA mú obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Chad kan tó jẹ́ ẹni ọgọ́rin… Ka siwaju