Ayẹyẹ Ọjọ àyájọ́ Awọn ọmọde àti EID tí ọdún ileya yìí : Gomina Ọyọ ṣe àdéhùn idaniloju pé awọn ọmọ ile-iwe ti wọn ji àti awọn olukọ ni igbiyanju ìtúsílẹ̀ wọn ti nlọ lọwọ.

Ayẹyẹ Ọjọ àyájọ́ Awọn ọmọde àti EID tí ọdún ileya yìí : Gomina Ọyọ ṣe àdéhùn idaniloju pé awọn ọmọ…

Ka siwaju

Ilé ẹjọ́ UK paṣẹ́ pé kí wọ́n lé àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà elẹ́wọ́n tí wọ́n jẹ̀bi ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ to pọ̀ lẹ́yìn ogun òfin ọlọ́jọ́ pípẹ́ padà sí Nàìjíríà .

Ilé Ẹjọ́ UK paṣẹ́ pé kí wọ́n dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n jẹ̀bi ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ pọ̀ sí i…

Ka siwaju

Ilé funfun Amerika wà lábẹ́ ewu ńlá :ọ̀pọ̀ ìbọn ń ró lakolako bí àwọn bí àwọn agbébọn kan ṣe yawọ agbègbè ilé funfun Amẹ́ríkà ti wọn fẹ pa Ààrẹ Trump.

Ilé funfun Amerika wà lábẹ́ ewu ńlá :ọ̀pọ̀ ìbọn ń ró lakolako bí àwọn bí àwọn agbébọn kan ṣe yawọ…

Ka siwaju

Trump ati orílẹ̀ èdè Iran ṣe àdéhùn dúnàdúrà láti ṣí ojú ọ̀nà tí gbogbo orílẹ̀ èdè lágbàáyé ń gbà gbé epo rọ̀bì kọjá (Strait Hormuz).

Trump ati orílẹ̀ èdè Iran ṣe àdéhùn dúnàdúrà láti ṣí ojú ọ̀nà tí gbogbo orílẹ̀ èdè lágbàáyé ń gbà láti…

Ka siwaju

Ilẹ̀ Yorùbá wà nínú ogun ,’ Ẹgbẹ́ Yorùbá kan Kegbe sí etí ìjọba Fun dídá ààbò bo ara ẹni, Àgbègbè láti kojú àwọn afẹ̀míṣòfò agbésùnmọ̀mí.

Ilẹ̀ Yorùbá wà nínú ogun ,’ Ẹgbẹ́ Yorùbá kan Kegbe sí etí ìjọba Fun dídá ààbò bo ara ẹni Àgbègbè…

Ka siwaju

Ọlọ́pàá pa ọ̀gá àwọn agbésùnmọ̀mí, wọn gba ibon àti owó tí iye jẹ́ N2m pẹ̀lú ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ lọ́wọ́ rẹ ni igbó orile- ilugun ìpínlẹ̀ Ogun

Ọlọ́pàá pa ọ̀gá àwọn agbésùnmọ̀mí, wọn gba ibon àti owó tí iye jẹ́ N2m pẹ̀lú ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ lọ́wọ́ rẹ ni…

Ka siwaju