Mo gbà ki jẹ koriko lábẹ́ aṣáájú Mùsùlùmí ju kí n jẹ ẹran-adìẹ lábẹ́ aṣáájú tí kì í ṣe Mùsùlùmí lọ’ — Onímọ̀ ẹ̀sìn Islam Almaliky ṣe àtìlẹ́yìn fún àjọṣepọ̀ Tinubu àti Shettima Muslim – Muslim ticket.

Mo gbà ki jẹ koriko lábẹ́ aṣáájú Mùsùlùmí ju kí n jẹ ẹran-adìẹ lábẹ́ aṣáájú tí kì í ṣe Mùsùlùmí…

Ka siwaju

Àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí gba 50 mílíọ̀nù náírà, àwọn ohun-mímu ẹlẹ́rìndòdò Malt àti oúnjẹ àti èso, kí wọ́n tó tú Adájọ́ Ilé-ẹjọ́ Gíga ti ìpínlẹ̀ Kebbi tí wọ́n jí gbé sílẹ̀ – Ìbátan rẹ̀ ṣàlàyé.

Àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí gba 50 mílíọ̀nù náírà, àwọn ohun-mímu ẹlẹ́rìndòdò Malt àti oúnjẹ èso kí wọ́n tó tú Adájọ́ Ilé-ẹjọ́…

Ka siwaju

Àárẹ̀ ilẹ̀ Amẹ́ríkà, Donald Trump, gboriyin fun ọba Morocco Mohammed VI, fún aṣeyọrí iṣẹ́ òpópónà ńlá kìlómítà (1,055)Tiznit-Dakhla, O kede ni ọjọ́ aiku pé wọ́n yóò sọ ọ̀nà gíga Tiznit-Dakhla tí orilẹ-èdè Morocco ní orúkọ òun.

Trump kede pe wọn yoo fun ọna nla Tiznit–Dakhla ni orukọ rẹ, o si dupẹ lọwọ Ọba Mohammed VI. Ààrẹ…

Ka siwaju

A wá láti ṣiṣẹ́, kì í ṣe láti kú’: Àwọn òṣìṣẹ́ ọmọ Nàìjíríà márùn-ún tí wọ́n di ẹni tí ó di mọ́ra ní ilẹ̀ òkèèrè ń bẹ̀bẹ̀ fún ìrànlọ́wọ́ láti ọ̀dọ̀ ìjọba Tinubu lẹ́yìn tí ẹlẹgbẹ́ wọn kan kú ní ilé-iṣẹ́ kan ní orílẹ̀ èdè Iraq.

A wá láti ṣiṣẹ́, kì í ṣe láti kú’: Àwọn òṣìṣẹ́ ọmọ Nàìjíríà márùn-ún tí wọ́n di ẹni tí ó…

Ka siwaju

Sípéènì jawe olubori, Agbabọọlu iwaju ẹgbẹ Argentina, Lionel Messi (ti o wọ nọmba 10), n ṣe afihan bi o ṣe n rilara lẹyin ti Spain bori ninu ere ipari idije ife ẹyẹ agbaye ti ọdun 2026 laarin Spain ati Argentina ni papa iṣere New York ni ọjọ kọkandinlogun oṣu Keje, ọdun 2026.

Agbabọọlu iwaju ẹgbẹ Argentina, Lionel Messi (ti o wọ nọmba 10), n ṣe afihan bi o ṣe n rilara lẹyin…

Ka siwaju

Àjọ tó ń kojú ọ̀rọ̀ oògùn olóró ní Nàìjíríà NDLEA mú obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Chad kan tó jẹ́ ẹni ọgọ́rin ọdún , tí wọ́n sì ń fẹ̀sùn kàn pé ó ń ta oògùn olóró, nígbà tí wọ́n ń ṣe ìgbésẹ̀ kárí-ìlẹ̀ láti dènà irú ìwà bẹ́ẹ̀.

Àjọ tó ń kojú ọ̀rọ̀ oògùn olóró ní Nàìjíríà NDLEA mú obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Chad kan tó jẹ́ ẹni ọgọ́rin…

Ka siwaju

Àwọn agbésùnmọ́mí yawọ ilé ìwé girima ni Kogi nígbà tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ń ṣe ìdánwò NECO, wọ́n sì jí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́rin, olórí ilé ìwé, àti alábóòjútò ìdánwò gbé lọ .

Àwọn agbésùnmọ́mí afemisofo Yabo Ilé-ìwé ní Kogi Lakoko ti awọn akẹ́kọ̀ọ́ ń ṣe idanwo NECO, wọ́n jí ọ̀gá àgbà ilé…

Ka siwaju