Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkìtì ti kéde ìsinmi lenu isẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ lónìí tíì ṣe ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gún oṣù kẹfà Ọdun 2026.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkìtì ti kéde ìsinmi lenu isẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ lónìí tíì ṣe ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gún oṣù kẹfà…

Ka siwaju

Àwọn agbébọn yawọ ilé ìjọsìn Christ Apostolic church Eda Oniyo ní ìpínlẹ̀ Èkìtì, wón pa Pásítọ̀ ìjọ, wọ́n jí ọ̀pọ̀lọpọ̀ olùjọsìn gbé lọ.Ní dédé ago mẹ́jọ àbọ̀ àṣálẹ́8:30pm, ọjọ́ ìṣẹ́gun .

Àwọn agbébọn yawọ ilé ìjọsìn Christ Apostolic church Eda Oniyo ní ìpínlẹ̀ Èkìtì, wón pa Pásítọ̀ ìjọ, wọ́n jí ọ̀pọ̀lọpọ̀…

Ka siwaju