A kò san owó-ìtúsílẹ̀ fun awon Agbésùnmọ̀mí , won mú méjọ nínú wọn , ti wọn sì pa awọn kan lára àwọn agbésùnmọ̀mí bi won se ji àwọn ọmọ ilé-ìwé àti olùkọ́ Oyo gbé , àwọn olùkọ́ si gba òmìnira pada – Tinubu President

A ko san owó-ìtúsílẹ̀ fun awon onijagidijagan Agbésùnmọ̀mí , won mú méjọ nínú wọn , ti sì pa awon kan…

Ka siwaju

Ọga agba iléèwé Ọyọ ti wọn jigbe pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sọ pé kii sẹ owo biliọnu kan naira,ọkọ̀ Hilux méjì àti òfin Sharia ni àwọn agbesunmobi ń bèrè fún ò.

Ọga agba ileewe Ọyọ ti wọn jigbe pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sọ pé kii sẹ owo biliọnu kan naira,ọkọ̀ Hilux méjì…

Ka siwaju