Aṣòfin Amẹrikà gbèrò ìwé-àṣẹ láti gbésẹ̀lé wí wọlé sí Amẹríkà láti awọn orílẹ̀ -èdè Áfíríkà mẹ́ta.

Aṣòfin Amẹrikà gbèrò ìwé-àṣẹ láti gbésẹ̀lé wí wọlé sí Amẹríkà láti awọn orílẹ̀ -èdè Áfíríkà mẹ́ta. Aṣofin orílẹ̀ -èdè Amẹrikà…

Ka siwaju

Awọn ikọlu Xenophobic: Awọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà 700 tun wa ni ìdàmú ni South Africa ti wọn ti rí ọkọ̀ òfurufú tí yóò gbé wọn àkókò gbedeke tí South Africa fún wọn ti ń parí.

Awọn ikọlu Xenophobic: Awọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà 700 tun wa ni ìdàmú ni South Africa ti wọn ti rí ọkọ̀…

Ka siwaju

Ijoba Nàìjíríà tí kó ipele Keji àwọn ọmọ orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà jáde kúrò ni South Africa Nítorí ìkọlù Xenophobic, wọ́n ti dé sí Èkó.

Ijoba Nàìjíríà tí kó ipele Keji àwọn ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà jáde kúrò ni South Africa Nitori ikọlu Xenophobic, wọ́n ti…

Ka siwaju

Ilé ẹjọ́ UK paṣẹ́ pé kí wọ́n lé àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà elẹ́wọ́n tí wọ́n jẹ̀bi ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ to pọ̀ lẹ́yìn ogun òfin ọlọ́jọ́ pípẹ́ padà sí Nàìjíríà .

Ilé Ẹjọ́ UK paṣẹ́ pé kí wọ́n dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n jẹ̀bi ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ pọ̀ sí i…

Ka siwaju

Arabinrin ọmọ Nàìjíríà tí kò nílé ní orílẹ̀-èdè Ítálì bẹ̀bẹ̀ pé kí wọ́n gbé òun padà sílè lẹ́yìn tí ó pàdánù pàdánù iṣẹ́, àkáǹtì báńkì ilé ifowopamo rẹ

Arabinrin ọmọ Nàìjíríà tí kò nílé ní orílẹ̀-èdè Ítálì bẹ̀bẹ̀ pé kí wọ́n gbé òun padà sílè lẹ́yìn tí ó…

Ka siwaju

Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá Nàìjíríà tí tu ibùdó àwọn Ẹgbẹ ti n ta ènìyàn, fi ọmọ ènìyàn ṣe owó ẹrú káàkiri Nàìjíríà ká , wọn gba àwọn ọmọ ara ilẹ̀ òkèèrè 30 là Ni Abuja àti ní Nasarawa.

Ọlọ́pàá náà sọ pe iwadii bẹ̀rẹ̀ lẹ́hìn àwọn ijabọ oye ti fi ipadanu ti ọpọlọpọ àwọn ọmọ ìlú òkèèrè láàrin…

Ka siwaju