Lórí ọ̀rọ̀ Ìjínigbé: MACBAN bẹ Gómìnà Ọ̀yọ́ , Makinde, fi ẹ̀sùn kan Sunday Igboho fún fífi ìwé àṣẹ sílẹ̀ láti halẹ̀ mọ́ àwùjọ Fulani.

Lórí ọ̀rọ̀ Ìjínigbéc: MACBAN bẹ Gómìnà Oyo, Makinde, fi ẹ̀sùn kan Sunday Igboho fún fífi ìwé àṣẹ sílẹ̀ láti halẹ̀…

Ka siwaju

Ìjà ńlá bẹ́ sílẹ̀ láàárín Hausa àti Yorùbá ni ọjọọ Ìbàdàn, Hausa fi ọ̀bẹ gún ọmọdékùnrin Yorùbá tó lọ ra indomie jẹ́ pa, tí wọ́n sì ń yinbon sókè lákọlàkọ.

Ìjà ńlá bẹ́ sílẹ̀ láàárín Hausa àti Yorùbá ni ọjọọ Ìbàdàn, Hausa fi ọ̀bẹ gún ọmọdékùnrin Yorùbá tó lọ ra…

Ka siwaju

Àwọn olóyè ilẹ̀ Ìbàdàn rọ olùdíje fún ipò Gómìnà Ọ̀yọ́ lábẹ́ asia ẹgbẹ́ APC Alli Sharafadeen láti ṣe pàtàkì ipá ti oyè ìbílẹ̀ ju erongba olóṣèlú lọ.

Àwọn olóyè rọ olùdíje fún ipò Gómìnà Ọ̀yọ́ lábẹ́ APC Alli Sharafadeen láti ṣe pàtàkì ipá ti oyè ìbílẹ̀ ju…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí ti jí ọ̀gá àgbà iléèwé àti àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ gbé lọ, ní ilé ìwé gírámà Ahoro – Esinele ní ìjọba ìbílẹ̀ Oriire ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Awọn Agbéṣùmọ̀mí ti ji ọ̀gá àgbà ilé ìwé ,àti àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbé lọ nilu Ahoro-Esinele ní ìjọba ìbílẹ̀ Oriire ìpínlẹ̀…

Ka siwaju