Boko Haram kede iku oluyaworan wọn ti àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà pa ninu ikọlu kan, Boko Haram ti kede iku Abu Salim al-Barnawi, oluyaworan kan ti awọn ọmọ-ogun Naijiria pa lakoko ikọlu kan.

Ni ọjọ́ kejìlelógún, oṣù keje ọdún 2026, ní àwọn ikọ̀ Boko Haram kede iku oluyaworan wọn ti wọn pa ninu…

Ka siwaju

Àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà mú obìnrin ọmọ orilẹ-èdè Chad tí wọ́n fẹ̀sùn kàn pé ó ń fún àwọn agbésùmọ́mí Boko Haram àti ISWAP ní, oúnjẹ, oògùn olóró àti ọtí líle ní Borno.

Ọwọ́ àwọn ológun orilẹ-èdè Nàìjíríà ti tẹ arábìnrin kàn Racheal Samuel ẹni ọdun mejidinlaadota(48), ọmọ orílẹ̀ èdè Chad 🇹🇩 ,Owo…

Ka siwaju

Àwọn olùkọ́ ní Ọ̀yọ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ wọn bí àníyàn ṣe ń pọ̀ sí lórí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ ti wọn ji gbé, Àwọn ilé ìwé ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tún ti ṣí sílẹ̀ lónìí, bí Ẹgbẹ́ Àwọn Olùkọ́ ní Nàìjíríà ((NUT) ti kéde

Àwọn ilé ìwé gbogbogbò ní Ìpínlẹ̀ Oyo tún ṣí sílẹ̀ lónìí, bí Ẹgbẹ́ Àwọn Olùkọ́ ní Nàìjíríà ti kéde ní…

Ka siwaju

Àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà tí operations Hadin Kai (OPHK) tí ṣe àṣeyọrí gba àwọn ọmọ ilé ìwé mẹ́wàá tó ń ṣe ìdánwò Neco àti àwọn olùkọ́ tí wọ́n jí gbé sílẹ̀.

Àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà tí operations Hadin Kai (OPHK) tí ṣe àṣeyọrí gba àwọn ọmọ ilé ìwé mẹ́wàá tó ń…

Ka siwaju