Boko Haram gé orí àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà, àwọn kan farapa yánnayànna bí wọ́n ṣe ṣe Ìkọlù sí ọgbà ológun ni kùtùkùtù òwúrọ̀ òní ọjọ́ Ẹtì ni ibùdó àwọn ọmọ ogun tó wà ni ìpínlè Borno.

Loni tíì ọjọ́ Ẹtì ọjọ́ Kàrún oṣù kẹfà ọdún 2026 ni àwọn Boko Haram gé orí àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà,…

Ka siwaju

Ọmọ Nàìjíríà tó wà ní UK, Adewale Anthony Sobogun ẹni ọdún (61yrs)rí ẹ̀wọ̀n ọdún méjìdínlọ́gbọ̀n(28yrs ) he, fún ẹ̀sùn ìfipábá ọmọdébìnrin méjì lò pọ̀.

Adewale Sobogun jẹ́ ẹni ọdún mọ́kànlélọ́gọ́ta, tí ó sì ti ń gbé orílẹ̀ èdè Biritiko( Uk) ti pẹ́. Ilé ẹjọ́…

Ka siwaju