Ìjà to ń lọ lọ́wọ́ pẹ̀lú Israel – Iran, Amẹ́ríkà Russia – Ukraine jẹ́ kí ó nira fún Ìjọba Nàìjíríà láti kojú àwọn agbéṣùmọ̀mí – Mínísítà fún ètò àbò Christopher Musa.

Ìjà to ń lọ lọ́wọ́ pẹ̀lú Israel – Iran, Amẹ́ríkà Russia – Ukraine jẹ́ kí ó nira fún Ìjọba Nàìjíríà…

Ka siwaju

Trump ati orílẹ̀ èdè Iran ṣe àdéhùn dúnàdúrà láti ṣí ojú ọ̀nà tí gbogbo orílẹ̀ èdè lágbàáyé ń gbà gbé epo rọ̀bì kọjá (Strait Hormuz).

Trump ati orílẹ̀ èdè Iran ṣe àdéhùn dúnàdúrà láti ṣí ojú ọ̀nà tí gbogbo orílẹ̀ èdè lágbàáyé ń gbà láti…

Ka siwaju

Trump ti dí ojú ọ̀nà tí orílẹ̀ èdè Iran lè gbà gbé epo rọ̀bì kọjá sí àwọn orílẹ̀ èdè mìíràn , bákan náà ni ó tún dí ibi tí Iran lè gbà gbé ọkọ ojú omi wọlé.

Ní alẹ́ ọjọ́ àìkú tíì ṣe ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 2026, ni iléeṣẹ́ ológun Amẹ́ríkà tún kéde wípé ìgbẹ́sẹ̀…

Ka siwaju