Àjọ NDLEA mú olokada arìnrìn-àjò to gbé egbògi olóró ń lọ òkè òkun, ọgọ́rùn 100 Methamphetamine ni wọ́n gba lọwọ rẹ tí iye owo jẹ́ N10.3billion ní èbúté ọkọ̀ ojú omi ìpínlẹ̀ Èkó .

Àjọ NDLEA mú olokada arìnrìn-àjò to gbé egbògi olóró ń lọ òkè òkun tí wọ́n gbà jáde láti ọwọ́ àwọn…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá Metro bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ “Kosaye” ní ìpínlẹ̀ Ogun, Èkó,wọ́n mú àwọn afurasi ọ̀daràn agbésùmọ́mí 88, wọ́n sì gba àwọn tí wọ́n jí gbé márùn-ún sílẹ̀.

Àwọn ọlọ́pàá Metro bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ “Kosaye” ní ìpínlẹ̀ Ogun, Èkó,wọ́n mú àwọn afurasi ọ̀daràn agbésùmọ́mí 88, wọ́n sì gba àwọn…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu ti yan Ìyà àárín Arinola Ogbara Banjoko gẹ́gẹ́ bí Alákóso aṣojú lórí ìgbìmò ìṣòwò pàsí pààrọ̀ ọjà ìpínlẹ̀ Èkó.

Ààrẹ Tinubu ti yan Ìyà àárín Arinola Ogbara Banjoko gẹ́gẹ́ bí Alákóso aṣojú lórí ìgbìmò ìṣòwò pàsí pààrọ̀ ọjà ìpínlẹ̀…

Ka siwaju