Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ogun Mú Ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ṣọ̀ alábò ọlọ́pàá tó fi ipá já ìbálé Ọ̀dọ́bìnrin Ẹni Ọdún mẹ́rìndínlógún [16], tí wọ́n sì gba ìbọn lọ́wọ́ rẹ̀.

Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ogun Mú Ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ṣọ̀ alábò tó fi ipá já ìbálé Ọ̀dọ́bìnrin Ẹni Ọdún mẹ́rìndínlógún , tí…

Ka siwaju

Ìtẹ̀jẹ̀ ti tó gẹ́’ – Awon araalu ń béèrè ìtúsílẹ̀ lẹsẹkẹsẹ àwọn ọmọ iléèwé Ọ̀yọ́ ti won ji gbé , àti àwọn olùkọ́ni.

Ìtẹ̀jẹ̀ ti tó gẹ́’ – Awon araalu ń béèrè ìtúsílẹ̀ lẹsẹkẹsẹ àwọn ọmọ iléèwé Ọ̀yọ́ ti won ji gbé ,…

Ka siwaju

Ìròyìn ni yàjóyàjó:Ibanujẹ ni agbègbè Ọyọ wà bi àwọn obi ti fi agbára lọ mú àwọn ọmọ wọn ọmọdé kúrò ni ilé-ìwé alákọ́bẹ̀ẹ̀rẹ̀ nítorí àwọn ikọlu àwọn agbésùnmọ̀mí tí wọ́n ní o ń ṣẹlẹ̀ ni gbogbo agbègbè Ajawa ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ .

Àwọn òbí tí fi agbára lọ mú àwọn ọmọ wọn ọmọdé kúrò ni ilé ìwé nítorí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìkọlù agbésùnmọ̀mí…

Ka siwaju

Ààrẹ ìgbìmọ̀ Yorùbá council bu ẹnu àtẹ́ lu ìkọlù tí àwọn agbésùnmọ̀mí afẹ̀míṣòfò ṣe sí ilé ẹ̀kọ́ ni Ọ̀yọ́, ó sì ké sí àpérò gbogbo àwọn Lobaloba nílẹ̀ Yorùbá .

ÀṢÀKẸ́ TV SHOW: Ààrẹ ìgbìmọ̀ Yorùbá council bu ẹnu àtẹ́ lu ìkọlù tí àwọn agbésùnmọ̀mí afẹ̀míṣòfò ṣe sí ilé ẹ̀kọ́…

Ka siwaju