Àwọn ọ̀gá ọlọ́pàá ń kọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ọlọ́pàá igba (200) lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìjà àti lílo ohun-ìjà láti kojú àwọn afẹ̀míṣòfò agbésùnmọ̀mí ní Kano.

Àwọn ọ̀gá ọlọ́pàá ń kọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ọlọ́pàá igba (200) lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìjà àti lílo ohun-ìjà láti kojú àwọn afẹ̀míṣòfò…

Ka siwaju

Àwọn jàǹdùnkú olóṣèlú pa olórí ọ̀dọ́ ẹgbẹ Accord Esa-Oke Ọ̀sun, Gómìnà Adeleke pé Komisona ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ọ̀sun Wole Oke, Oyetola, Oyebamiji àti àwọn mìíràn fún apero, ṣe abewo sí àwọn ẹbí .

Gomina Adeleke pe Komisana olopaa, Wole Oke, Oyetola, Oyebamiji, ati awon mi-in nitori ipaniyan òṣèlú ìpínlẹ̀ Ọ̀sun Gomina Ademola Adeleke…

Ka siwaju

Arábìnrin Shifawu Alabi ẹni Àádọ́rin Ọdún tó sọnù ni ọjà ọba Ìbàdàn ni wọ́n rí ní Ọ̀sun iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ ọ̀sun ló kéde rẹ̀.

Arábìnrin ìyá àgbàlagbà kan ẹni Àádọ́rin Ọdún Shifawu Alabi tí ó sọnu tí àwọn ẹbí ń wá ní Ọjà ọba…

Ka siwaju