Ọọ̀ni Adeyeye Eniitan Ogunwunsi Ọ̀jájá 11 tí késí ìjọba àpapọ̀ láti fòpin sí ètò àbò tó mẹ́hẹ àti bí ìwà jagidijagan àwọn ìwà ọ̀daràn mìíràn ṣe ń dàgbàsókè si lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Ọọ̀ni Adeyeye Eniitan Ogunwunsi Ọ̀jájá 11 tí késí ìjọba àpapọ̀ láti fòpin sí ètò àbò tó mẹ́hẹ àti bí ìwà…

Ka siwaju

Ìjọba ìpínlẹ̀ Borno tí bójú àànú wo àwọn agbésùnmọ̀mí Oòkóléní Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin 720 àti àwọn tó jẹ́ alátìleyìn fún wọn 992 pẹ̀lú àwọn ọmọ wọn 2,050 ni wọn dapadà sínú Awujọ.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Borno tí bójú àànú wo àwọn agbésùnmọ̀mí Oòkóléní Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin 720 àti àwọn tó jẹ́ alátìleyìn fún wọn 992…

Ka siwaju

Ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Atuchukwu Onyeanusi tí wọ ẹ̀wọ̀n L’ámẹ́ríkà fún jìbìtì ilokulo ìwé ìwọ̀lú lílo ìwé idanimọ tí wọ́n jí àti àwọn ìwé ẹ̀tàn mìíràn láti gba iṣẹ́ ní Amẹ́ríkà.

Ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Atuchukwu Onyeanusi tí wọ ẹ̀wọ̀n L’ámẹ́ríkà fún jìbìtì ilokulo ìwé ìwọ̀lú lílo ìwé idanimọ tí wọ́n…

Ka siwaju

Ọga agba iléèwé Ọyọ ti wọn jigbe pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sọ pé kii sẹ owo biliọnu kan naira,ọkọ̀ Hilux méjì àti òfin Sharia ni àwọn agbesunmobi ń bèrè fún ò.

Ọga agba ileewe Ọyọ ti wọn jigbe pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sọ pé kii sẹ owo biliọnu kan naira,ọkọ̀ Hilux méjì…

Ka siwaju

Boko Haram gé orí àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà, àwọn kan farapa yánnayànna bí wọ́n ṣe ṣe Ìkọlù sí ọgbà ológun ni kùtùkùtù òwúrọ̀ òní ọjọ́ Ẹtì ni ibùdó àwọn ọmọ ogun tó wà ni ìpínlè Borno.

Loni tíì ọjọ́ Ẹtì ọjọ́ Kàrún oṣù kẹfà ọdún 2026 ni àwọn Boko Haram gé orí àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà,…

Ka siwaju