Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Borno mú àwọn ọkùnrin márùn-ún tó wọ aṣọ tí wọ́n kọ pé ‘Tinubu Must Go’ (Tinubu gbọ́dọ̀ kúrò ní ipò) sí, wọ́n sì ti fi wọ́n sẹ́wọ̀n.

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Borno mú àwọn ọkùnrin márùn-ún tó wọ aṣọ tí wọ́n kọ pé ‘Tinubu Must Go’ (Tinubu…

Ka siwaju

Ilé ẹjọ́ UK, da Babatunde Odutola, ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà kan, lẹbi ẹ̀wọ̀n ọ̀sẹ̀ mẹ́rìnlélógójì ni UK lẹyin ti o jẹwọ pé òun ṣe iṣe ifẹ tí ó sì ń fi nkan ọmọkùnrin rẹ ṣeré pẹlu ara rẹ ni iwájú obìnrin kan nínú ọkọ̀ ojú-irin.

Ọmọ orilẹ-ede Naijiria ti ngbe ni UK, wọn da a lẹbi ẹwọn ọsẹ mẹrinlelogoji fun ṣiṣe iṣe ifẹ pẹlu ara…

Ka siwaju

Àwọn ènìyàn mẹ́rìnlélógún kú lẹ́yìn tí wọ́n mu ‘àgbo oògùn ìbílẹ̀ ’ ní Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ odigbo ìpínlẹ̀ Ondo.

Àwọn ènìyàn mẹ́rìnlélógún kú lẹ́yìn tí wọ́n mu ‘oògùn ìbílẹ̀ ’ kan ní Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ odigbo ìpínlẹ̀ Ondo. Ní…

Ka siwaju

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Osun fẹ́ pé EFCC si ilé -ẹjọ́ lórí dídi banki ifowopamo ìjọba Ọ̀sun mú ní àwọn ọjọ́ díẹ̀ ṣáájú ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun .

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Osun fẹ́ pé EFCC sí ilé – ẹjọ́ lórí dídi àkọọ́lẹ̀ ifowopamo ìjọba Ọ̀sun mú ní àwọn ọjọ́…

Ka siwaju

Arákùnrin Agbe kan ni ipinle Kogi ti o tun jẹ́ ọmọ-ogun Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí ti lo ọjọ́ márùndínlógójì lé ní igba 235 ni ọwọ́ awọn ajinigbe, nigba ti ẹbi rẹ n duro de igba ti wọn yoo gba a là.

Arákùnrin Agbe kan ni ipinle Kogi ti o tun jẹ́ ọmọ-ogun tẹ́lẹ̀ rí ti lo ọjọ́ márùndínlógójì lé ní igba…

Ka siwaju

Àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí gba 50 mílíọ̀nù náírà, àwọn ohun-mímu ẹlẹ́rìndòdò Malt àti oúnjẹ àti èso, kí wọ́n tó tú Adájọ́ Ilé-ẹjọ́ Gíga ti ìpínlẹ̀ Kebbi tí wọ́n jí gbé sílẹ̀ – Ìbátan rẹ̀ ṣàlàyé.

Àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí gba 50 mílíọ̀nù náírà, àwọn ohun-mímu ẹlẹ́rìndòdò Malt àti oúnjẹ èso kí wọ́n tó tú Adájọ́ Ilé-ẹjọ́…

Ka siwaju