Gómìnà Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ Seyi Makinde ni àárọ̀ òní tíì ṣe ọjọ́ Àbámẹ́ta, Ọgbọ̀n ọjọ́ Oṣù Kàrún 2026, kó Ọgọọgọrun àwọn ọkọ̀ ayọkẹlẹ tí ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn irinṣẹ ìbániẹnisọ̀rọ̀ fún àwọn ilé isẹ ààbò ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ pẹ̀lú àwọn ọlọ́pàá.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ Seyi Makinde ni àárọ̀ òní tíì ṣe ọjọ́ Àbámẹ́ta, Ọgbọ̀n ọjọ́ Oṣù Kàrún 2026, kó Ọgọọgọrun àwọn…

Ka siwaju

Ọwọ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ogun tẹ Abdullahi Muhammadu Seriki Fulani Ijebu Ode àti ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, wọn ri àpò owó tí wọ́n fi gba owó ìtúsílẹ̀ “Ransom “níbi ilé ìdáná rẹ̀.

Ọwọ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ogun tẹ Abdullahi Muhammadu Seriki Fulani Ijebu Ode àti ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, wọn ri àpò owó tí…

Ka siwaju

Orílẹ̀ èdè Morocco tí borí South Africa bí Morocco ṣe gba ipò kinni nínú ètò ọrọ ajé, ìdàgbàsókè inú ìlú, ilé isẹ, isẹ ìṣelọ́pọ̀ jẹ́ olùdarí ni gbogbo ilẹ̀ Afrika.

Orílẹ̀ èdè Morocco tí borí South Africa bí Morocco ṣe gba ipò kinni nínú ètò ọrọ ajé, ìdàgbàsókè inú ìlú,…

Ka siwaju

Awọn ọmọ ile-iwe ń ṣubu lulẹ̀ lakoko ayẹyẹ àyájọ́ Ọjọ Awọn ọmọde, Ọ̀pọ̀ àwọn ọmọdé, ọmọ ilé ìwé ló dákú, bí wọn ṣe yín Tajútajú nibi ayẹyẹ àyájọ́ Awọn ọmọde ni . Edo.

Iberu lo wa ni papa isere Samuel Ogbemudia, lojoru Wesde, nigba ti a gbo wi pe awon akekoo kan subu…

Ka siwaju

Ayẹyẹ Ọjọ àyájọ́ Awọn ọmọde àti EID tí ọdún ileya yìí : Gomina Ọyọ ṣe àdéhùn idaniloju pé awọn ọmọ ile-iwe ti wọn ji àti awọn olukọ ni igbiyanju ìtúsílẹ̀ wọn ti nlọ lọwọ.

Ayẹyẹ Ọjọ àyájọ́ Awọn ọmọde àti EID tí ọdún ileya yìí : Gomina Ọyọ ṣe àdéhùn idaniloju pé awọn ọmọ…

Ka siwaju