Àwọn olùwádìí fi ẹ̀sùn kan Siyaka, olórí àjọ NSCDC ní ìpínlẹ̀ Niger, fún fífi ènìyàn kún ibi tí ó pọ̀ jù àti fífúnni ní ìròyìn èké nípa àìsàn kan, lẹ́yìn tí àwọn òṣìṣẹ́-méènù (miners) 33 kú nígbà tí wọ́n wà lábẹ́ àmójútó wọn.

Àwọn olùwádìí fi ẹ̀sùn kan Siyaka, olórí àjọ NSCDC ní ìpínlẹ̀ Niger, fún fífi ènìyàn kún ibi tí ó pọ̀…

Ka siwaju

Àwọn agbésùmọ́mí kọ́ ló wà nínú fọ́nrán tí ara ìlú ń gbé kiri lórí ayélujára àwọn ọdẹ figilantes ní – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Nàìjíríà takò fọ́nrán náà.

Àwọn agbésùmọ́mí kọ́ ló wà nínú fọ́nrán tí ara ìlú ń gbé kiri lórí ayélujára àwọn ọdẹ figilantes ní –…

Ka siwaju