ÀWỌN ÌRÒYÌN TÍ Ó NÍPA Ilé ẹjọ́ pàṣẹ fún àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà láti gbé ẹjọ́ sájẹ́ǹtì ọlọ́pàá tí ó pa Kabiru awakọ, kí wọ́n sì san owó ìtanràn igba mílíọ̀nù náírà N200M fún pípa awakọ̀ ọkọ̀ akẹ́rù Kabiru Babai ní ọdún 2021 ní ìpínlẹ̀ Osun. Asake Jul 3, 2026 0 Ilé ẹjọ́ pàṣẹ fún àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà láti gbé ẹjọ́ sájẹ́ǹtì, kí wọ́n sì san owó mílíọ̀nù igba N200M fún… Ka siwaju