Àjọ tó ń kojú ọ̀rọ̀ oògùn olóró ní Nàìjíríà NDLEA mú obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Chad kan tó jẹ́ ẹni ọgọ́rin ọdún , tí wọ́n sì ń fẹ̀sùn kàn pé ó ń ta oògùn olóró, nígbà tí wọ́n ń ṣe ìgbésẹ̀ kárí-ìlẹ̀ láti dènà irú ìwà bẹ́ẹ̀.

Àjọ tó ń kojú ọ̀rọ̀ oògùn olóró ní Nàìjíríà NDLEA mú obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Chad kan tó jẹ́ ẹni ọgọ́rin…

Ka siwaju

Àwọn agbésùnmọ́mí jí àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà mẹ́ta gbé ní Zamfara , wọ́n sì béèrè fún owó ìtúsílẹ̀ 50 mílíọ̀nù.

Àwọn agbésùnmọ́mí jí àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà mẹ́ta gbé ní Zamfara , wọ́n sì béèrè fún owó ìtúsílẹ̀ 50 mílíọ̀nù.…

Ka siwaju

Gbogbo ọmọ ogun Nàìjíríà tó bá dúró de àṣẹ kí ó tó yinbọn pa àwọn apànìyàn agbésùmọ́mí ni wọ́n máa ń ṣe bí ọlọ́ṣà – Minisita fún ààbò Musa Christopher

Gbogbo ọmọ ogun Naijiria tó bá dúró de àṣẹ kí ó tó yinbọn sí àwọn apànìyàn agbésùmọ́mí ni wọ́n máa…

Ka siwaju