Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu pàṣẹ fún gbogbo àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà lati gba awọn ọkọ ayọkẹlẹ ti wọn ko ni nọmba ni gbogbo orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu pàṣẹ fún gbogbo àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà lati gba awọn ọkọ ayọkẹlẹ ti wọn ko ni nọmba…

Ka siwaju

Boko Haram gé orí àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà, àwọn kan farapa yánnayànna bí wọ́n ṣe ṣe Ìkọlù sí ọgbà ológun ni kùtùkùtù òwúrọ̀ òní ọjọ́ Ẹtì ni ibùdó àwọn ọmọ ogun tó wà ni ìpínlè Borno.

Loni tíì ọjọ́ Ẹtì ọjọ́ Kàrún oṣù kẹfà ọdún 2026 ni àwọn Boko Haram gé orí àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà,…

Ka siwaju

Awọn agbebọn ji iyawo,àti awọn ọmọ ibeji arákùnrin àbúrò minisita fún ètò iná mọ̀nàmọ́ná tẹlẹri Adebayo Adelabu gbé lọ nilu Ìbàdàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Awọn agbebọn ji iyawo,àti awọn ọmọ ibeji arákùnrin àbúrò minisita fún ètò iná mọ̀nàmọ́ná tẹlẹri Adebayo Adelabu gbé lọ nilu…

Ka siwaju

Seyi Makinde bu ẹnu atẹ lu awọn ọrọ ti Fayose sọ , lórí àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọtí àwọn agbésùmọ́mí jí gbé ní Ọ̀yọ́, o rọ ara ilu kí wọn gbàdúrà fun un.

Makinde bu ẹnu atẹ lu awọn ọrọ ti Fayose sọ , lórí àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọ́ tí…

Ka siwaju

Bokoharam kéde pé àwọn fẹ́ ṣe ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́ Al-Quran fún ọgọ́rùn-ún (100) nínú àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ tí wọ́n jí gbé ní ìjọba Kaiama Kwara I to tí kẹ́kọ̀ọ́ yege ni àhámọ́ wọn.

Bokoharam kéde pé àwọn fẹ́ ṣe ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́ Al-Quran fún ọgọ́rùn-ún (100) nínú àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ tí…

Ka siwaju