Ọlọ́pàá Nàìjíríà ti jẹ́rìí sí ìtúsílẹ̀ àwọn olùjọ́sìn CAC Eda Oniyo ní Ìpínlẹ̀ Ekiti lẹ́yìn tí wọ́n ti lo oṣù mélòó kan pẹ̀lú nínú ìgbèkùn àwọn agbésùnmọ̀mí.

Ọlọ́pàá Nàìjíríà ti jẹ́rìí sí ìtúsílẹ̀ àwọn olùjọ́sìn CAC Eda Oniyo ní Ìpínlẹ̀ Ekiti lẹ́yìn tí wọ́n ti lo oṣù…

Ka siwaju

Orúkọ 104 àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà ni kíkùn ni Iléeṣẹ́ ológun kọ síta pé wọ́n pàdánù pẹ̀lú àwọn ìbọn iṣẹ wọn ọ̀sé kan lẹ́hìn ìkọlù ti Boko Haram ṣe sí Ibùdó ológun Borno.

orúkọ 104 àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà ni kíkùn ni Iléeṣẹ́ ológun kọ síta pé wọ́n pàdánù pẹ̀lú àwọn ìbọn iṣẹ…

Ka siwaju

Awọn ikọlu Xenophobic: Awọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà 700 tun wa ni ìdàmú ni South Africa ti wọn ti rí ọkọ̀ òfurufú tí yóò gbé wọn àkókò gbedeke tí South Africa fún wọn ti ń parí.

Awọn ikọlu Xenophobic: Awọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà 700 tun wa ni ìdàmú ni South Africa ti wọn ti rí ọkọ̀…

Ka siwaju

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkìtì ti kéde ìsinmi lenu isẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ lónìí tíì ṣe ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gún oṣù kẹfà Ọdun 2026.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkìtì ti kéde ìsinmi lenu isẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ lónìí tíì ṣe ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gún oṣù kẹfà…

Ka siwaju

Olùdíje fún ipò Gómìnà Ọ̀yọ́ lábẹ́ asia ẹgbẹ́ òṣèlú Accord , Oriyomi Hamzat, Tako ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn pé ó ní àwọn ọna asopọ Kan si Afurasí adigunjalè ‘Surri Ilupeju’.

Olùdíje fún ipò Gómìnà Ọ̀yọ́ lábẹ́ asia ẹgbẹ́ òṣèlú Accord , Oriyomi Hamzat, Tako ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn pé…

Ka siwaju

Gómìnà Katsina Radda ní kí àwọn agbésùnmọ̀mí gbé ohun ìjà ọwọ́ wọn sílẹ̀, kí wọ́n padà sí ọ̀dọ̀ àwọn ẹbí wọn gẹ́gẹ́ bí ìjọba ṣe ṣèlérí àtitìlẹ́yìn.

Gómìnà Katsina Radda ní kí àwọn agbésùnmọ̀mí gbé ohun ìjà ọwọ́ wọn sílẹ̀, kí wọ́n padà sí ọ̀dọ̀ àwọn ẹbí…

Ka siwaju