Lábẹ́ ìṣàkóso Tinubu, APC lè pàdánù ìbò àwọn ipinlẹ kan ni Gúsù -ÌwọÒòrùn , ko si si ohun ti yóò ṣẹlẹ̀, ilé ayé kò nítorí rẹ̀ wó tàbí parẹ́ — Gómìnà Èkó , Sanwo-Olu

Lábẹ́ Tinubu, APC lè pàdánù ìbò àwọn ipinlẹ kan ni Gúsù -ÌwọÒòrùn , ko si si ohun ti yóò ṣẹlẹ̀,…

Ka siwaju

Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá mú àwọn òṣìṣẹ́ ọlọ́pàá mẹ́rin lẹ́yìn tí fídíò wọn jáde sórí ayélujára tó fi ẹ̀tanú ẹlẹ́yàmẹyà hàn, fa ìbínú gbígbóná janjan, tí wọ́n sì ń bèrè owo lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà tó ń bọ̀ láti UK.

Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá mú àwọn òṣìṣẹ́ ọlọ́pàá mẹ́rin lẹ́yìn tí fídíò wọn jáde sórí ayélujára tó fi ẹ̀tanú ẹlẹ́yàmẹyà hàn, fa…

Ka siwaju

Ile igbimo Aṣoju Pé Mínísítà fún Ọrọ Ajeji ati Olùdámọ̀ràn Ààbò Orilẹ-èdè (NSA) wá fún Ìbéèrè lori Ìwádìí PFIPC ti a pe ni ‘Eke’.

Ile igbimo Aṣoju Pé Mínísítà fún Ọrọ Ajeji ati Olùdámọ̀ràn Ààbò Orilẹ-èdè (NSA) wá fún Ìbéèrè lori Ìwádìí PFIPC ti…

Ka siwaju

Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ondo mú àwọn ọ̀daràn mẹ́ta tí wọ́n máa ń ja àwọn ènìyàn ní olè lọ́nà, wọ́n gba àwọn ìbọn àti ọkọ̀ lọ́wọ́ wọn, wọ́n sì tún mú àwọn afurà méje mìíràn.

Ogunjọ́ 20 Oṣù Keje, Ọdún 2026ÌròyìnÓ sọ pé wọ́n dá àwọn afurasi náà dúró nígbà tí wọ́n ń rìnrìn-àjò nínú…

Ka siwaju

Àwọn ọ̀gá ọlọ́pàá ń kọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ọlọ́pàá igba (200) lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìjà àti lílo ohun-ìjà láti kojú àwọn afẹ̀míṣòfò agbésùnmọ̀mí ní Kano.

Àwọn ọ̀gá ọlọ́pàá ń kọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ọlọ́pàá igba (200) lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìjà àti lílo ohun-ìjà láti kojú àwọn afẹ̀míṣòfò…

Ka siwaju

Àjọ tó ń kojú ọ̀rọ̀ oògùn olóró ní Nàìjíríà NDLEA mú obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Chad kan tó jẹ́ ẹni ọgọ́rin ọdún , tí wọ́n sì ń fẹ̀sùn kàn pé ó ń ta oògùn olóró, nígbà tí wọ́n ń ṣe ìgbésẹ̀ kárí-ìlẹ̀ láti dènà irú ìwà bẹ́ẹ̀.

Àjọ tó ń kojú ọ̀rọ̀ oògùn olóró ní Nàìjíríà NDLEA mú obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Chad kan tó jẹ́ ẹni ọgọ́rin…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́ta tí wọ́n jí gbé ní Ẹdo sílẹ̀ , wọ́n sì pa ẹni tí wọ́n fura sí pé ó jí wọn gbé.

Àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́ta tí wọ́n jí gbé ní Ẹdo sílẹ̀ , wọ́n sì pa ẹni tí…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí jí òkú ọ̀gágun FRSC Augustine Ikwue àti àwọn ènìyàn tó ń ṣọ̀fọ̀ gbé lọ ní Kogi, wọ́n sì béèrè fún owó ìtúsílẹ̀ 450 mílíọ̀nù.

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí jí òkú ọ̀gágun FRSC Augustine Ikwue àti àwọn ènìyàn tó ń ṣọ̀fọ̀ gbé lọ ní Kogi, wọ́n sì…

Ka siwaju