Àwọn jàǹdùnkú olóṣèlú yìnbon pa Ọ̀dọ́mọdékùnrin Ezekiel Olapade ẹni ọdun mẹ́rìnlá ,tí ẹlòmíràn si farapa yánnayànna lágbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Irepodun n’ilu Ilobu ìpínlẹ̀ Ọ̀sun.

Àwọn jàǹdùnkú olóṣèlú yìnbon pa Ọ̀dọ́mọdékùnrin,tí ẹlòmíràn si farapa yánnayànna lágbègbè LG Secretariat ní Ọ̀sun. Rògbòdìyàn ṣẹlẹ̀ nítòsí ẹnu ọ́nà…

Ka siwaju

Remi Tinubu pin ọkọ bọ̀gìnì ayọkẹlẹ N7. 7bn fún awọn aṣáájú obìnrin ẹgbẹ́ òṣèlú APC ni àwọn ìpínlẹ̀ márùn-ún tí ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò ń dárí .

Remi Tinubu pin ọkọ bọ̀gìnì ayọkẹlẹ N7. 7bn fún awọn aṣáájú obìnrin ẹgbẹ́ òṣèlú APC ni àwọn ìpínlẹ̀ márùn-ún tí…

Ka siwaju

Ọọ̀ni Adeyeye Eniitan Ogunwunsi Ọ̀jájá 11 tí késí ìjọba àpapọ̀ láti fòpin sí ètò àbò tó mẹ́hẹ àti bí ìwà jagidijagan àwọn ìwà ọ̀daràn mìíràn ṣe ń dàgbàsókè si lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Ọọ̀ni Adeyeye Eniitan Ogunwunsi Ọ̀jájá 11 tí késí ìjọba àpapọ̀ láti fòpin sí ètò àbò tó mẹ́hẹ àti bí ìwà…

Ka siwaju

Davido gba ìsinmi lenu isẹ orin kíkọ láti ṣáájú àwọn ọ̀dọ́ ìpínlẹ̀ ọ̀sun fún ìpolongo ìbò 2027 ipò Gómìnà sáà kejì àbúrò bàbá rẹ̀ Ademola Adeleke.

ÀṢÀKẸ́ TV SHOW: Davido gba ìsinmi lenu isẹ orin kíkọ láti ṣáájú àwọn ọ̀dọ́ ìpínlẹ̀ ọ̀sun fún ìpolongo ìbò 2027…

Ka siwaju

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀sun ti rọ Ọba Gbenga Oloyede tìlú Ipetumodu lóye, látàrí ẹ̀sùn jìbìtì owó COVID19 tí ó gbé ọba lọ ẹ̀wọ̀n L’ámẹ́ríkà.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀sun ti gbé Ọba Gbenga Oloyede kúrò lórí ìtẹ́ ọba gẹ́gẹ́ bí Apetumodu ti Ipetumodu ni ìjọba ìbílẹ̀…

Ka siwaju

Àwọn ìdílé òye méjì Fagbemirokun àti Aribile fún ìjọba Ọ̀sun ní gbèdéke ọjọ́ méje láti rọ ọba Ipetumodu Oloyede tó wà lẹ́wọ̀n L’ámẹ́ríkà lóyè.

Àwọn ìdílé ọmọ òye Fagbemirokun àti Aribile fún ìjọba Ọ̀sun ní gbèdéke ọjọ́ méje péré láti rọ Apetu tí Ipetumodu…

Ka siwaju