Tinubu sọ fún Gómìnà Ademola Adeleke lórí ìpè fóònù pé òun ti pàṣẹ fún EFCC láti ṣí àkọọ́lẹ̀ ifowopamo owó ìjọba ìpínlẹ̀ Osun tí wọ́n ti pa tẹ́lẹ̀ sílẹ̀ .

Tinubu sọ fún Adeleke nípasẹ̀ ìpè lórí fóònù pé òun ti pàṣẹ fún EFCC láti ṣí àkọọ́lẹ̀ ifowopamo owó ìjọba…

Ka siwaju

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Osun fẹ́ pé EFCC si ilé -ẹjọ́ lórí dídi banki ifowopamo ìjọba Ọ̀sun mú ní àwọn ọjọ́ díẹ̀ ṣáájú ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun .

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Osun fẹ́ pé EFCC sí ilé – ẹjọ́ lórí dídi àkọọ́lẹ̀ ifowopamo ìjọba Ọ̀sun mú ní àwọn ọjọ́…

Ka siwaju

Ó pọn dandan fún APC láti borí nínú ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun,’ Alága Àpapọ̀ sọ bẹ́ẹ̀; ó ní wọn yóò kó àwọn Gómìnà, àwọn Àgbà-òjíṣẹ́, àti àwọn mìíràn wá láti kópa nínú ìdìbò náà.’A gbọ́dọ̀ borí nínú ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun fún ẹgbẹ́ APC,’ ni Alága Orílẹ̀-èdè sọ; yóò sì kó àwọn Gómìnà, àwọn Mínísítà, àti àwọn mìíràn wá láti kópa nínú ìdìbò náà.

Ó pọn dandan fún APC láti borí nínú ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun,’ Alága Àpapọ̀ sọ bẹ́ẹ̀; ó ní wọn yóò kó…

Ka siwaju

Ilé ẹjọ́ pàṣẹ fún àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà láti gbé ẹjọ́ sájẹ́ǹtì ọlọ́pàá tí ó pa Kabiru awakọ, kí wọ́n sì san owó ìtanràn igba mílíọ̀nù náírà N200M fún pípa awakọ̀ ọkọ̀ akẹ́rù Kabiru Babai ní ọdún 2021 ní ìpínlẹ̀ Osun.

Ilé ẹjọ́ pàṣẹ fún àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà láti gbé ẹjọ́ sájẹ́ǹtì, kí wọ́n sì san owó mílíọ̀nù igba N200M fún…

Ka siwaju