Imam Mọ́ṣáláṣí Lọndọnu Abdul Khan ti rí ẹ̀wọ̀n Ogún ọdún he, fún ẹ̀sùn ìfipábá àwọn ọmọdébìnrin lo pọ̀.

Ilé ẹjọ́ Snaresbrook Crown nilu Lọndọnu tí ju Imam Mọ́ṣáláṣí Lọndọnu Abdul Khan sí ẹ̀wọ̀n Ogún ọdún fún ẹ̀sùn ìfipábá…

Ka siwaju

Olùsọàgùntàn Pásítọ̀ Amos Isah tí wọ́n fi ẹ̀sùn kan pé ó fipa bá ọmọ ọdun mẹ́rìnlá lò pọ̀ nílé ìjọsìn Labuja, lọ ṣe àbẹ̀wò sí ìdílé ọmọ náà ní alẹ́ láti bẹ̀bẹ̀ fún ìdáríjì.

FÍDÍÒ ṣàfihàn Olusoagutan Amos Isah, ti wọn fẹ̀sùn kan pé o fipa bá ọmọ ọdun mẹ́rìnlá 14 yrs lò pọ̀…

Ka siwaju