Ilé ẹjọ́ UK paṣẹ́ pé kí wọ́n lé àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà elẹ́wọ́n tí wọ́n jẹ̀bi ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ to pọ̀ lẹ́yìn ogun òfin ọlọ́jọ́ pípẹ́ padà sí Nàìjíríà .

Ilé Ẹjọ́ UK paṣẹ́ pé kí wọ́n dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n jẹ̀bi ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ pọ̀ sí i…

Ka siwaju

Ọmọ Nàìjíríà tó wà ní UK, Adewale Anthony Sobogun ẹni ọdún (61yrs)rí ẹ̀wọ̀n ọdún méjìdínlọ́gbọ̀n(28yrs ) he, fún ẹ̀sùn ìfipábá ọmọdébìnrin méjì lò pọ̀.

Adewale Sobogun jẹ́ ẹni ọdún mọ́kànlélọ́gọ́ta, tí ó sì ti ń gbé orílẹ̀ èdè Biritiko( Uk) ti pẹ́. Ilé ẹjọ́…

Ka siwaju