Awọn ikọlu Xenophobic: Awọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà 700 tun wa ni ìdàmú ni South Africa ti wọn ti rí ọkọ̀ òfurufú tí yóò gbé wọn àkókò gbedeke tí South Africa fún wọn ti ń parí.

Awọn ikọlu Xenophobic: Awọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà 700 tun wa ni ìdàmú ni South Africa ti wọn ti rí ọkọ̀…

Ka siwaju

Alakoso Iléeṣẹ́ Ologun Amẹrikà ṣe abẹwo sí Nàìjíríà fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ìlọṣíwájú tí ètò ààbò ati ajọṣepọ láàrin orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Amẹrikà ní ìgbìyànjú láti kojú àwọn agbésùmọ́mí.

Alakoso Ologun Amẹrikà ṣe abewo sí Nàìjíríà fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ìlọṣíwájú tí ètò ààbò ati ajọṣepọ láàrin orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti…

Ka siwaju

Ìjọba Tinubu jẹwọ owó-iṣẹ oṣù ti o kéré julọ N70,000 Ko tó fún ọrọ-aje mọ, wọn ṣe àwọn ifihan si àwọn ìjíròrò tuntun lórí owó òṣìṣẹ́ .

Gbajiamila ṣe ìfihàn náà ní ọjọ́rú nígbí tí ó ń ṣojú fún Ààrẹ Tinubu níbi ìpàdé ìjọba tí Working People…

Ka siwaju

Àwọn agbésùmọ́mí kọ́ ló wà nínú fọ́nrán tí ara ìlú ń gbé kiri lórí ayélujára àwọn ọdẹ figilantes ní – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Nàìjíríà takò fọ́nrán náà.

Àwọn agbésùmọ́mí kọ́ ló wà nínú fọ́nrán tí ara ìlú ń gbé kiri lórí ayélujára àwọn ọdẹ figilantes ní –…

Ka siwaju

Awọn ọmọ Naijiria tó wà nínú atimọle ní orílẹ̀ èdè India tí ké gbàjarè síta, fi ẹ̀sùn kan Ile-iṣẹ ọlọ́pàá pé wọ́n tí Kọ wọn silẹ, Sọ pe O kéré tán 400 ọmọ Nàìjíríà ló wà nínú àhámọ́ ní Ibùdó Deportation.

Awọn ọmọ Naijiria tó wà nínú atimọle ní orílẹ̀ èdè India fi ẹ̀sùn kan Ile-iṣẹ ọlọ́pàá pé wọ́n tí Kọ…

Ka siwaju

Gómìnà Katsina Radda ní kí àwọn agbésùnmọ̀mí gbé ohun ìjà ọwọ́ wọn sílẹ̀, kí wọ́n padà sí ọ̀dọ̀ àwọn ẹbí wọn gẹ́gẹ́ bí ìjọba ṣe ṣèlérí àtitìlẹ́yìn.

Gómìnà Katsina Radda ní kí àwọn agbésùnmọ̀mí gbé ohun ìjà ọwọ́ wọn sílẹ̀, kí wọ́n padà sí ọ̀dọ̀ àwọn ẹbí…

Ka siwaju