Àwọn ọlọ́pàá mú olùdásílẹ̀ akoonu (content creator) ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ‘Odogwu ti Asaba’ lórí ẹ̀sùn ìfipábá ọ̀dọ́mọbìnrin ọmọ ogun ọdun lò pọ̀ tí ọmọbìnrin náà sì pa ara rẹ̀ lẹ́yìn náà.

Àwọn ọlọ́pàá mú olùdásílẹ̀ akoonu (content creator) ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ‘Odogwu ti Asaba’ lórí ẹ̀sùn ìfipábá ọ̀dọ́mọbìnrin ọmọ ogun ọdun…

Ka siwaju

Awon agbésùnmọ̀mí ji ọ̀gá ilé ẹ̀kọ́ gíga Ọ̀gbẹ́ni Kolawole Matthew gbé ní Ìjọ́ba Ìbílẹ̀ itesiwaju ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, wọ́n bèrè fún 30millionu owó ìtúsílẹ̀.

Àwọn agbésùnmọ́mí jí olórí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Ọ̀yọ́ gbé, wọ́n sì béèrè owó ìtúsílẹ̀ N30m Àwọn agbésùnmọ́mí tí wọ́n fura sí…

Ka siwaju

Alakoso Iléeṣẹ́ Ologun Amẹrikà ṣe abẹwo sí Nàìjíríà fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ìlọṣíwájú tí ètò ààbò ati ajọṣepọ láàrin orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Amẹrikà ní ìgbìyànjú láti kojú àwọn agbésùmọ́mí.

Alakoso Ologun Amẹrikà ṣe abewo sí Nàìjíríà fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ìlọṣíwájú tí ètò ààbò ati ajọṣepọ láàrin orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti…

Ka siwaju