Mínísítà tuntun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn fún iná mọ̀nàmọ́ná Joseph Tegbe figbe ta, Mi kò ṣèlérí pé iná yóò fún oṣù mẹ́ta fún ọmọ Nàìjíríà o.

Minisita ti wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ yan fun Agbára iná mànàmáná , Joseph Olasunkanmi Tegbe, ti kọ awọn iroyin ti o sọ…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu ti yan Ìyà àárín Arinola Ogbara Banjoko gẹ́gẹ́ bí Alákóso aṣojú lórí ìgbìmò ìṣòwò pàsí pààrọ̀ ọjà ìpínlẹ̀ Èkó.

Ààrẹ Tinubu ti yan Ìyà àárín Arinola Ogbara Banjoko gẹ́gẹ́ bí Alákóso aṣojú lórí ìgbìmò ìṣòwò pàsí pààrọ̀ ọjà ìpínlẹ̀…

Ka siwaju

Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu ń wá àjọṣepọ̀ ìfọwọ́sowopọ̀ àwọn ọlọ́pàá àti àwọn ará ìlú ní gbogbo agbègbè láti ní ètò ààbò tó péye nínú Nàìjíríà.

Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu, n wá , ajọṣepọ ìfọwọ́sowopo àwọn ọlọ́pàá àti àwọn ará ìlú agbègbè láti ni ètò ààbò…

Ka siwaju

Iléeṣẹ́ ọmọ ogun Nàìjíríà ṣe ìdókowò ní ìmọ̀ ẹ̀rọ drone àti àwọn ètò ìgbàlódé láti mú kí ètò àbò tó péye wà nínú ììlú.

ÀṢÀKẸ́ TV NEWS : Idoko-owo ọmọ-ogun ni awọn drones lati jẹki awọn iṣẹ ṣiṣe – COASỌ̀gá iléeṣẹ́ ológun Lieutenant General…

Ka siwaju

Iléeṣẹ́ ọmọ ogun Nàìjíríà ṣe ìkìlọ̀ fún àwọn ọmọ ogun Lodi si lílo ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ àwùjọ láti gbójú síta lórí ayélujára.

ÀṢÀKẸ́ TV SHOW: Iléeṣẹ́ ọmọogun Nàìjíríà ṣe ìkìlọ̀ fún àwọn ọmọ ogun Lodi si lilo ẹ̀rọ ibanisoro àwùjọ láti gbójú…

Ka siwaju

Peter obi lára àwọn oludije fún ipò Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ti kéde ìfipòslẹ̀ rẹ̀ nínú ẹgbẹ́ òṣèlú African Democratic Congress ADC.

Peter obi ọ̀kan lára àwọn Oludije fún ipo Ààrẹ Nàìjíríà, ti kéde ifiposile re nínú ẹgbẹ́ òṣèlú African Democratic Congress…

Ka siwaju