Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Borno mú àwọn ọkùnrin márùn-ún tó wọ aṣọ tí wọ́n kọ pé ‘Tinubu Must Go’ (Tinubu gbọ́dọ̀ kúrò ní ipò) sí, wọ́n sì ti fi wọ́n sẹ́wọ̀n.

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Borno mú àwọn ọkùnrin márùn-ún tó wọ aṣọ tí wọ́n kọ pé ‘Tinubu Must Go’ (Tinubu…

Ka siwaju

Àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí gba 50 mílíọ̀nù náírà, àwọn ohun-mímu ẹlẹ́rìndòdò Malt àti oúnjẹ àti èso, kí wọ́n tó tú Adájọ́ Ilé-ẹjọ́ Gíga ti ìpínlẹ̀ Kebbi tí wọ́n jí gbé sílẹ̀ – Ìbátan rẹ̀ ṣàlàyé.

Àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí gba 50 mílíọ̀nù náírà, àwọn ohun-mímu ẹlẹ́rìndòdò Malt àti oúnjẹ èso kí wọ́n tó tú Adájọ́ Ilé-ẹjọ́…

Ka siwaju

Awọn Agbéṣùnmọ̀mí ji awọn ọmọ ile-iwe mẹjọ ti Gateway ICT Polytechnic gbe ni ipinlẹ Ogun, ile-iwe náà si fagilé àwọn ìdánwò tí wọ́n fẹ́ ṣe ni ọjọ́bọ̀ .

Awọn Agbéṣùnmọ̀mí ji awọn ọmọ ile-iwe mẹjọ ti Gateway ICT Polytechnic gbe ni ipinlẹ Ogun, ile-iwe náà si fagilé àwọn…

Ka siwaju

Ọlọ́pàá Hisbah tí ìpínlẹ̀ Sokoto tí fi òfin de fífúnni ni ẹ̀bùn nígbà ètò ìfihàn ọkọ̀ àti ìyàwó àti lílo olorin DJ níbi ayẹyẹ ìgbéyàwó, wọ́n fi òfin de kí obìnrin jòkó sí ẹgbẹ awakọ̀ kẹ̀kẹ́ Napel.

Ọlọ́pàá Hisbah tí ìpínlẹ̀ Sokoto tí fi òfin de fífúnni ni ẹ̀bùn nígbà ètò ìfihàn ọkọ̀ àti ìyàwó àti lílo…

Ka siwaju

Ìyàlẹ́nu bo gbogbo ènìyàn bí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Yunifásítì Jos ṣe dáyà jẹ ẹlẹgbẹ́ wọn títí ó fi kú nítorí ẹ̀rọ ibanisoro iPhone kan tí ó sọnù; àwọn ọlọ́pàá sì dákẹ́ jẹ́ẹ́.

Ìyàlẹ́nu bo gbogbo ènìyàn bí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Yunifásítì Jos ṣe dáyà jẹ ẹlẹgbẹ́ wọn títí ó fi kú nítorí ẹ̀rọ…

Ka siwaju

Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà Nàìjíríà tí fọwọ́sí ìwé òfin lati fi òfin de ìwàásù nínú àwọn ọkọ̀ èrò ìrìn àjò gbogboogbò, ẹni tí ó bá tapa sòfin yóò san Àádọ́ta ẹgbẹ̀rún náírà.

Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà Nàìjíríà tí fọwọ́sí ìwé òfin lati fi òfin de ìwàásù nínú àwọn ọkọ̀ èrò ìrìn àjò…

Ka siwaju

Àjọ tó ń kojú ọ̀rọ̀ oògùn olóró ní Nàìjíríà NDLEA mú obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Chad kan tó jẹ́ ẹni ọgọ́rin ọdún , tí wọ́n sì ń fẹ̀sùn kàn pé ó ń ta oògùn olóró, nígbà tí wọ́n ń ṣe ìgbésẹ̀ kárí-ìlẹ̀ láti dènà irú ìwà bẹ́ẹ̀.

Àjọ tó ń kojú ọ̀rọ̀ oògùn olóró ní Nàìjíríà NDLEA mú obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Chad kan tó jẹ́ ẹni ọgọ́rin…

Ka siwaju

‘A gbọ́ igbe olùkọ́ wa kí wọ́n tó pa á’: Akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ìwé kan láti Ìbàdàn tí wọ́n gbà là ṣàlàyé nípa àwọn ìṣẹ́jú tó gbẹ̀yìn olùkọ́ Michael Oyedokun.

‘A gbọ́ igbe olùkọ́ wa kí wọ́n tó pa á’: Akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ìwé kan láti Ìbàdàn tí wọ́n gbà là ṣàlàyé…

Ka siwaju