Mo gbà ki jẹ koriko lábẹ́ aṣáájú Mùsùlùmí ju kí n jẹ ẹran-adìẹ lábẹ́ aṣáájú tí kì í ṣe Mùsùlùmí lọ’ — Onímọ̀ ẹ̀sìn Islam Almaliky ṣe àtìlẹ́yìn fún àjọṣepọ̀ Tinubu àti Shettima

Mo gbà ki jẹ koriko lábẹ́ aṣáájú Mùsùlùmí ju kí n jẹ ẹran-adìẹ lábẹ́ aṣáájú tí kì í ṣe Mùsùlùmí…

Ka siwaju

Ìdìbò ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Obìnrin oníwà-ipá jàǹdùnkú olóṣèlú kan tí wọ́n ń pè ní ‘Arugba’ halẹ̀ mọ́ àwọn olùdìbò pé òun yóò gé ìka ọwọ́ wọn tí wọn kò bá dìbò fún ẹgbẹ́ APC.

Ìdìbò ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Obìnrin oníwà-ipá jàǹdùnkú olóṣèlú kan tí wọ́n ń pè ní ‘Arugba’ halẹ̀ mọ́ àwọn olùdìbò pé…

Ka siwaju

Amnesty International tún rọ àwọn aláṣẹ ní Nàìjíríà láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ-ìlú nígbà ìdìbò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Osun.

Amnesty International tún rọ àwọn aláṣẹ ní Nàìjíríà láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ-ìlú nígbà ìdìbò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Osun.…

Ka siwaju

Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Àwọn ọlọ́pàá pe Sẹ́nátọ̀ Fadahunsi ti ẹgbẹ́ APC wá fún ìbéèrè lórí ọ̀rọ̀ ìhalẹ̀ láti pa àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Accord.

Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Àwọn ọlọ́pàá pe Sẹ́nátọ̀ Fadahunsi ti ẹgbẹ́ APC wá fún ìbéèrè lórí ọ̀rọ̀ ìhalẹ̀ láti pa…

Ka siwaju

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Adeleke, fi ẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá pé wọ́n ní ètò láti mú àwọn aṣáájú ẹgbẹ́ òṣèlú Accord kí wọ́n sì fi wọ́n sẹ́wọ̀n ní Abuja títí tí ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun yóò fi parí.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Adeleke, fi ẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá pé wọ́n ní ètò láti mú àwọn aṣáájú ẹgbẹ́ òṣèlú Accord…

Ka siwaju

Tinubu sọ fún Gómìnà Ademola Adeleke lórí ìpè fóònù pé òun ti pàṣẹ fún EFCC láti ṣí àkọọ́lẹ̀ ifowopamo owó ìjọba ìpínlẹ̀ Osun tí wọ́n ti pa tẹ́lẹ̀ sílẹ̀ .

Tinubu sọ fún Adeleke nípasẹ̀ ìpè lórí fóònù pé òun ti pàṣẹ fún EFCC láti ṣí àkọọ́lẹ̀ ifowopamo owó ìjọba…

Ka siwaju

Ìròyìn pàtàkì : Kaiama KwaraÀwọn obìnrin àti ọmọdé mẹ́rindínlọ́gọ́sàn 176 tí àwọn agbésùnmọ́mí jí gbé láti àdúgbò Woro, Nuku ní ìpínlẹ̀ Kwara ti gba ìtúsílẹ̀ òmìnira wọn padà lẹ́yìn oṣù mẹ́fà.

Àwọn ènìyàn mẹ́rindínlọ́gọ́sàn 176 ti àwọn agbésùnmọ́mí ji gbé láti àwọn agbègbè Woro ati Nuku, ìjọba ìbílẹ̀ Kaiama ni Ìpínlẹ̀…

Ka siwaju

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Osun fẹ́ pé EFCC si ilé -ẹjọ́ lórí dídi banki ifowopamo ìjọba Ọ̀sun mú ní àwọn ọjọ́ díẹ̀ ṣáájú ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun .

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Osun fẹ́ pé EFCC sí ilé – ẹjọ́ lórí dídi àkọọ́lẹ̀ ifowopamo ìjọba Ọ̀sun mú ní àwọn ọjọ́…

Ka siwaju