Ìròyìn fi hàn pé ní ọdún kan, àwọn èèyàn 7,825 ló jẹ́ olùfaragbá tí wọ́n jí gbé (kidnapping) ní Nàìjíríà, àwọn 1,142 sì pàdánù ẹ̀mí wọn, nígbà tí wọ́n san owó ìtúsílẹ̀ tó tó bíi bílíọ̀nù 7.8 náírà.

Ìròyìn fi hàn pé ní ọdún kan, àwọn èèyàn 7,825 ló jẹ́ olùfaragbá tí wọ́n jí gbé (kidnapping) ní Nàìjíríà,…

Ka siwaju

Àwọn agbésùnmọ́mí jí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn gbé nígbà àdúrà Jumu’ah ní àwọn àdúgbò kan ní Niger lẹ́yìn tí àwọn olùgbé kọ̀ láti san owó-orí tàbí láti tẹ̀lé àwọn ìlànà ẹ̀sìn kan — Gẹ́gẹ́ bí àwọn orísun ìròyìn ṣe sọ.

Àwọn agbésùnmọ́mí jí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn gbé nígbà àdúrà Jumu’ah ní àwọn àdúgbò kan ní Niger lẹ́yìn tí àwọn olùgbé kọ̀…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà ti jẹ́rìí sí i pé àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí jí àwọn olùjọ́sìn gbé ní mọ́ṣáláṣí ní Borgu nígbà tí wọ́n ń ṣe àdúrà Júmáàtì.

Àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà ti jẹ́rìí sí i pé àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí jí àwọn olùjọ́sìn gbé mọ́ṣáláṣí ní Borgu nígbà tí…

Ka siwaju

Adájọ́ kan ni ilẹ̀ Amẹrika ti ṣeto àkókò ìparí tuntun fun ìtúsílẹ̀ àwọn ìwé -ipamọ to rọ̀mọ́ àwọn ẹ̀sùn ti o so Tinubu mọ ọ̀rọ̀ gbígbé oogun olóró káàkiri àgbáyé – Ilé-iṣẹ́ ti n ṣiṣẹ́ fún Atiku ni Amẹrika ló gbé ọ̀rọ̀ náà síta .

Adájọ́ kan ni ilẹ̀ Amẹrika ti ṣeto àkókò ìparí tuntun fun ìtúsílẹ̀ àwọn ìwé -ipamọ to rọ̀mọ́ àwọn ẹ̀sùn ti…

Ka siwaju

Mo gbà ki jẹ koriko lábẹ́ aṣáájú Mùsùlùmí ju kí n jẹ ẹran-adìẹ lábẹ́ aṣáájú tí kì í ṣe Mùsùlùmí lọ’ — Onímọ̀ ẹ̀sìn Islam Almaliky ṣe àtìlẹ́yìn fún àjọṣepọ̀ Tinubu àti Shettima Muslim – Muslim ticket.

Mo gbà ki jẹ koriko lábẹ́ aṣáájú Mùsùlùmí ju kí n jẹ ẹran-adìẹ lábẹ́ aṣáájú tí kì í ṣe Mùsùlùmí…

Ka siwaju