Amnesty International tún rọ àwọn aláṣẹ ní Nàìjíríà láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ-ìlú nígbà ìdìbò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Osun.

Amnesty International tún rọ àwọn aláṣẹ ní Nàìjíríà láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ-ìlú nígbà ìdìbò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Osun.…

Ka siwaju

Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Àwọn ọlọ́pàá pe Sẹ́nátọ̀ Fadahunsi ti ẹgbẹ́ APC wá fún ìbéèrè lórí ọ̀rọ̀ ìhalẹ̀ láti pa àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Accord.

Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Àwọn ọlọ́pàá pe Sẹ́nátọ̀ Fadahunsi ti ẹgbẹ́ APC wá fún ìbéèrè lórí ọ̀rọ̀ ìhalẹ̀ láti pa…

Ka siwaju

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Adeleke, fi ẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá pé wọ́n ní ètò láti mú àwọn aṣáájú ẹgbẹ́ òṣèlú Accord kí wọ́n sì fi wọ́n sẹ́wọ̀n ní Abuja títí tí ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun yóò fi parí.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Adeleke, fi ẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá pé wọ́n ní ètò láti mú àwọn aṣáájú ẹgbẹ́ òṣèlú Accord…

Ka siwaju

Tinubu sọ fún Gómìnà Ademola Adeleke lórí ìpè fóònù pé òun ti pàṣẹ fún EFCC láti ṣí àkọọ́lẹ̀ ifowopamo owó ìjọba ìpínlẹ̀ Osun tí wọ́n ti pa tẹ́lẹ̀ sílẹ̀ .

Tinubu sọ fún Adeleke nípasẹ̀ ìpè lórí fóònù pé òun ti pàṣẹ fún EFCC láti ṣí àkọọ́lẹ̀ ifowopamo owó ìjọba…

Ka siwaju

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Osun fẹ́ pé EFCC si ilé -ẹjọ́ lórí dídi banki ifowopamo ìjọba Ọ̀sun mú ní àwọn ọjọ́ díẹ̀ ṣáájú ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun .

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Osun fẹ́ pé EFCC sí ilé – ẹjọ́ lórí dídi àkọọ́lẹ̀ ifowopamo ìjọba Ọ̀sun mú ní àwọn ọjọ́…

Ka siwaju

Mi ò ní àwáwí kankan fún dídènà ètò àkókò ṣáá kẹta ipò Ààrẹ tí Obasanjo’ fẹ́ lọ — Atiku dáhùn padà, ó sì sọ pé òun ló pese aṣọ fún ààrẹ àtijọ́ náà, tí ó sì tì í lẹ́yìn nígbà tí ó jáde nínú ẹ̀wọ̀n.

Mi ò ní àwáwí kankan fún dídènà ètò àkókò ṣáá kẹta ipò Ààrẹ tí Obasanjo’ fẹ́ lọ — Atiku dáhùn…

Ka siwaju

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ekiti, Oyebanji, ló ní ọwọ́ nínú bí wọ́n ṣe jí ìyá mi gbé — Ọmọbìnrin Olawumi, ẹni tí ó ti fìgbà kan díje dupò Gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́ APC, ké gbàjarè síta, ó sì ń bẹ̀bẹ̀ fún ìtúsílẹ̀ rẹ̀.

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn náà rèé lẹ́kùn rẹ́rẹ́: Ọjọ́ kẹta oṣù Kẹjọ, ọdún 2026ÌròyìnOlolade ṣàlàyé pé àwọn ọkùnrin tí a kò mọ̀,…

Ka siwaju

A kò san owó-ìtúsílẹ̀ fun awon Agbésùnmọ̀mí , won mú méjọ nínú wọn , ti wọn sì pa awọn kan lára àwọn agbésùnmọ̀mí bi won se ji àwọn ọmọ ilé-ìwé àti olùkọ́ Oyo gbé , àwọn olùkọ́ si gba òmìnira pada – Tinubu President

A ko san owó-ìtúsílẹ̀ fun awon onijagidijagan Agbésùnmọ̀mí , won mú méjọ nínú wọn , ti sì pa awon kan…

Ka siwaju