Amẹ́ríkà ń múra láti mú àwọn òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ aṣojú rẹ̀ àti àwọn ẹbí wọn kúrò ní Saudi Arabia àti àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn nítorí àwọn ìkọlù láti ọ̀dọ̀ àwọn Houthi.

Amẹ́ríkà ń múra láti mú àwọn òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ aṣojú rẹ̀ àti àwọn ẹbí wọn kúrò ní Saudi Arabia àti àwọn…

Ka siwaju

Wọn yìnbọn pa àwọn a ìbejì ọkùnrin tí wọ́n ni Ekhayeni Lounge Bar ní Gúúsù Áfíríkà;(south Áfíríkà) àwọn ọlọ́pàá ti bẹ̀rẹ̀ sí ní wá àwọn tó ṣe iṣẹ́ láabi náà.

Yìnbọn pa àwọn ìbejì ọkùnrin tí wọ́n ni Ekhayeni Lounge Bar ní Gúúsù Áfíríkà;(south Áfíríkà) àwọn ọlọ́pàá ti bẹ̀rẹ̀ sí…

Ka siwaju

Trump pe Ile-ẹjọ̀ Ọ̀daràn àgbáyé (ICC) ní ‘ibi’ (ohun burúkú), ó sì béèrè pé kí àwọn ọmọ-ẹgbẹ̀ rẹ̀ fi ipò wọn sílẹ̀ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.

Trump pe Ile-ẹjọ̀ Ọ̀daràn Kariaye (ICC) ní ‘ibi’ (ohun burúkú), ó sì béèrè pé kí àwọn ọmọ-ẹgbẹ̀rẹ rẹ̀ fi ipò…

Ka siwaju

Ilé ẹjọ́ UK, da Babatunde Odutola, ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà kan, lẹbi ẹ̀wọ̀n ọ̀sẹ̀ mẹ́rìnlélógójì ni UK lẹyin ti o jẹwọ pé òun ṣe iṣe ifẹ tí ó sì ń fi nkan ọmọkùnrin rẹ ṣeré pẹlu ara rẹ ni iwájú obìnrin kan nínú ọkọ̀ ojú-irin.

Ọmọ orilẹ-ede Naijiria ti ngbe ni UK, wọn da a lẹbi ẹwọn ọsẹ mẹrinlelogoji fun ṣiṣe iṣe ifẹ pẹlu ara…

Ka siwaju

Ọlọ́pàá Canada mú ọkùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33) fún ẹ̀sùn ìfipábá-ni-lòpọ̀ sí obìnrin méjì, tí kò tíì pé ọmọ ọdún méjìdínlógún, ní orílẹ̀-èdè Kánádà(Canada).

Ọlọ́pàá Canada mú ọkùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33) fún ẹ̀sùn ìfipábá-ni-lòpọ̀ sí obìnrin méjì,…

Ka siwaju

Ìjọ Redeem RCCG ṣètọrẹ, wọ́n san $265,854 láti gbé awọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà 500 kúrò ni South Africa lákòókò àwọn ìkọlù tí ó dá lórí ìkórira sí àwọn àjèjì.

Ìjọ Redeem RCCG ṣètọrẹ, wọ́n san $265,854 láti gbé awọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà 500 kúrò ni South Africa lákòókò àwọn…

Ka siwaju