Ààrẹ Tinubu ti buwọ́lu N2bn owó gbà má bínú àtìlẹyìn ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn 27 tí àwọn agbésùnmọ̀mí pa ni March 29,ọjọ́ ìsinmi ọ̀pẹ (palm Sunday) ní Plateau .

Ààrẹ Bola Tinubu ti buwọ́lu N2bn ni àtìlẹyìn iranlọwọ owó gbà má bínú fún àwọn olóògbé 27 tí àwọn agbésùnmọ̀mí…

Ka siwaju

Àwọn ẹlẹ́ṣọ àbò Aṣọ́gbó ti farapa yannayanna,Won pa ènìyàn méjì, tí wọ́n sì tún jí àwọn aráàlú gbé lọ ní ọsan gangan nígbà tí àwọn agbésùnmọ̀mí kọlù Oko Erese oro- àgọ́, Babanla Kwara.

Awọn ará ìlú ti o ba oníròyìn sọrọ sọ pe ìṣẹ̀lẹ̀ náà wáyé ni ọsan ọjọ ìṣẹ́gun, ọjọ́ kejìdnlogbon oṣù…

Ka siwaju

Àwọn agbébọn yawọ ilé ìjọsìn Christ Apostolic church Eda Oniyo ní ìpínlẹ̀ Èkìtì, wón pa Pásítọ̀ ìjọ, wọ́n jí ọ̀pọ̀lọpọ̀ olùjọsìn gbé lọ.Ní dédé ago mẹ́jọ àbọ̀ àṣálẹ́8:30pm, ọjọ́ ìṣẹ́gun .

Àwọn agbébọn yawọ ilé ìjọsìn Christ Apostolic church Eda Oniyo ní ìpínlẹ̀ Èkìtì, wón pa Pásítọ̀ ìjọ, wọ́n jí ọ̀pọ̀lọpọ̀…

Ka siwaju

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀sun ti rọ Ọba Gbenga Oloyede tìlú Ipetumodu lóye, látàrí ẹ̀sùn jìbìtì owó COVID19 tí ó gbé ọba lọ ẹ̀wọ̀n L’ámẹ́ríkà.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀sun ti gbé Ọba Gbenga Oloyede kúrò lórí ìtẹ́ ọba gẹ́gẹ́ bí Apetumodu ti Ipetumodu ni ìjọba ìbílẹ̀…

Ka siwaju