Seyi Makinde ṣe ifilọ́lẹ̀ àti fifisílẹ̀ ọ́fíìsí Ẹ̀ka ẹ̀ṣọ́ ààbò tuntun láti kojú àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ̀mí ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ .

Ní kùtùkùtù òní tíì ṣe ọjọ́ Abameta ọjọ́ keridinlogun oṣù Kàrún ọdún 2026 ni Seyi Makinde ṣe ifilọlẹ ati fifisilẹ…

Ka siwaju

Iléeṣẹ́ ọmọ ogun Nàìjíríà ṣe ìdókowò ní ìmọ̀ ẹ̀rọ drone àti àwọn ètò ìgbàlódé láti mú kí ètò àbò tó péye wà nínú ììlú.

ÀṢÀKẸ́ TV NEWS : Idoko-owo ọmọ-ogun ni awọn drones lati jẹki awọn iṣẹ ṣiṣe – COASỌ̀gá iléeṣẹ́ ológun Lieutenant General…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí jí arabinrin kan Olanike Ogundare gbé lọ nínú ilé rẹ ní ìpínlẹ̀ Èkó.Wọn kí àwọn ẹbí rẹ san N60Millionu owó ìtúsílẹ̀ rẹ.

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí jí arabinrin kan gbé lọ nínú ilé rẹ L’eko, lẹ́yìn ti wọ́n borí àwọn ẹlẹ́ṣọ àbò agbègbè náà…

Ka siwaju